CLEANSE THE TEMPLE
THE SEED
“Or do you not know that your body is the temple of the Holy Spirit who is in you, whom you have from God, and you are not your own? For you were bought at a price; therefore glorify God in your body and in your spirit, which are God’s.” 1 Corinthians 6:19-20 NKJV
The temple referred to in the above scripture is not the temple that is built with earthly materials but rather, our body which God desires to make His abode. 1 Cor 3:16 says know ye not that ye are the temple of God, and that the Spirit of God dwells in you? For God to continually dwell in the temple of our body, it needs to be cleansed and free of impurities. This requires a conscious effort from us, God won’t do it for us, rather we need to show interest in the cleansing process by intentionally getting rid of anything obvious to us that can make us unclean in God’s presence. The Psalmist says, Who shall ascend into the hill of the Lord or who shall stand in his holy place? It is people with clean hands and pure hearts. Sin is what contaminates this temple and the eyes of our God do not behold sin. The fact is, if this temple is not clean or cleansed, God cannot dwell there and if God does not dwell there, it becomes an abode for the devil because he is full of filthiness and when this happens, such a temple cannot produce good fruit. The devil is always looking for an avenue to contaminate an unguarded or loose temple with various forms of iniquities which may look like fun to us, but the end thereof is destruction. A loose temple is available to all forms of dangers that are dangerous, not to God but to us, therefore clean your temple today and allow Jesus to dwell in it.
FỌ TẸMPILI MỌ
IRUGBIN NAA
Tàbí ẹ̀yìn kò mọ̀ pé ara yín ní tempili Ẹ̀mí Mimọ, tí nbẹ nínú yín, tí ẹ̀yìn tí gbà lọwọ Ọlọrun? ẹ̀yìn kí i sí ṣe tí ara yin. Nítorí a ti rà yín ní iye kàn: nítorí náà ẹ yìn Ọlọ́run lógo nínú ara yín, ati nínú ẹ̀mí yín, tí ńṣe tí Ọlọ́run.” 1 KORINTI 6:19-20
Tẹmpili ti a tọka si ninu iwe-mimọ ti o wa loke kii ṣe tẹmpili ti a kọ pẹlu awọn ohun elo ti ye ṣugbọn dipo èyí tẹmpili jẹ ara wa ti Ọlọrun fẹ lati fi ṣé ibùgbé Rẹ 1 Korinti 3: 16 sọ pe Ẹ̀yin kó mọ́ pe Tẹmpili Ọlọrun lí ẹyin iṣẹ ati pe Ẹ̀mí Ọlọ́run ń gbé inú yín?
Nítorí kí Ọlọ́run lè máa gbé inú Tẹ́ńpìlì ara wa nígbà gbogbo, a nílò láti wẹ̀ ẹ mọ́, kí á sì bọ́ lọ́wọ́ àwọn èérí. Eyi nilo igbiyanju to dánilójú lati ọdọ wa, Ọlọrun ki yíò ṣe fun wa, dipo rẹ a nilo lati fi inú dídún han nipa ìsọdi mímọ, yiyọ ohunkohun ti o han gbangba si wa kuro, èyí ti o le sọ wa di aìmọ ni iwaju Ọlọrun. Onísáàmù sọ pé, “Ta ni yíò gun okè lọ sí orí òkè Olúwa tàbí ta ni yíò dúró ní ibi mímọ́ rẹ̀? O jẹ eniyan ọlọwọ mimọ ati àyà fúnfún. Ẹṣẹ ni ohun ti o nba tẹmpili yi jẹ, oju Ọlọrun wa ki i ri ẹṣẹ. Tí tẹmpili yi ko ba mọ, tabi kí a ti sọ ọ di mimọ, Ọlọ́run ko le gbe ni ibẹ, ati pe ti Ọlọrun ko ba gbe ni ibẹ, yio di ibùgbé fun Eṣu; nitori pe o kun fun ẹ̀gbin ati nigbati eyi ba ṣẹlẹ iru tẹmpili bẹ ko le so eso rere. Èṣù nigbagbogbo n wa ọna lati ba tẹmpili ti ko ni aabo jẹ́; tabi ti orisirisi ènìyàn nwọ, pẹlu oniruuru awọn iwa aiṣedede ti o le dabi igbadun fun wa ṣugbọn opin rẹ ni iparun. Tẹmpili alaiduro ṣinṣin, wa fun gbogbo awọn ewu, ewu èyí tí kii ṣe fun Ọlọrun bikoṣe si awa, nitorinaa wẹ tẹmpili rẹ mọ loni ki o gba Jesu laaye lati gbe inu rẹ.
BIBELI KIKA: Sáàmù 24:3-6.
ADURA: Olúwa ràn mí lọ́wọ́ láti sọ ara mi di mímọ́, àti láti múra sílẹ̀ fún ìfẹ́ Rẹ nígbà gbogbo. Amin.