DARE TO BELIEVE

THE SEED

“Daniel made up his mind not to let himself become ritually unclean by eating the food and drinking the wine of the royal court, so he asked Ashpenaz to help him…” — Daniel 1:8 GNB

Daniel chose to stand out and trust God for an outcome that seemed impossible. He and his friends decided to do what others didn’t dare to try. God honoured their faith and proved Himself strong. Many times, what seems “impossible” only remains so until someone steps out in faith. God backs up those who dare to trust Him beyond fear, tradition, or the crowd. Be the person who acts in faith—and you’ll see God do the extraordinary.

BIBLE READINGS: Daniel 1:8–20

PRAYER: Heavenly Father, give me bold faith to step out and trust You in every situation. Amen.

 

NÍ ÌGBOYÀ LÁTI GBAGBỌ

IRUGBIN NAA

” Ṣùgbọ́n Daniẹli pinnu ní ọkàn ara rẹ̀ pé òun kò ní ba ara òun jẹ́ pẹ̀lú oúnjẹ àti wáìnì ọba, nígbà náà ni ó gba ààyè lọ́wọ́ olórí àwọn ìwẹ̀fà wí pé òun kò fẹ́ ba ara òun jẹ́ ní ọ̀nàyìí.DÁNÍÉḶ Ì1:8

Daniẹli pinnu lati ya ara re sot ̣ọ̀ , ki o si gbẹkẹle Ọlọrun fun abajade ti ó dabi ẹnipe

ko ṣee ṣe. Oun ati awọn ọrẹ rẹ pinnu lati ṣe ohun ti awọn miiran ko nì igboya lati dánwo. Ọlọrun bu ọla fun igbagbọ wọn o si fi ara Rẹ hàn ni alagbara. Ni ọpọlọpọ igba, ohun ti ò dabi ẹni pé “ko ṣee ṣe” máa nwà bẹ́ẹ titi di igba ti ẹnikan yio fí igboya kò o lojù pèḷú igbagbọ. Ọlọrun máa n ṣe atilẹyin fun awọn wọnni ti wọn ni igboya lati gbẹkẹ wọ́n le e ju ẹ̀rù, aṣa, tabi ogunlọgọ àwọn ènìyàn. Jẹ́, eniyan ti yio gbé igbesẹ ninu igbagbọ- iwọ yoo rii pe Ọlọrun nṣe ohun iyalẹnu.

BIBELI KIKA: Dáníẹlì 1:8–20 ́

ADURA: Baba Ọrun, fun mi ni igbagbọ igboya lati tesiwaju lati gbekele Ọ ni gbogbo ipo. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *