DISCOVER YOUR GOD-GIVEN LIMITS
THE SEED
“…He did this so that they would look for Him, and perhaps find Him as they felt about for Him. Yet God is actually not far from any one of us…” — Acts 17:27 GNB
God has set the boundaries of your existence—not to limit you, but to draw you closer to Him. His purpose for your life is far greater than what you can see now. You can only reach those divine boundaries through partnership with Him. Your true capacity is found in God, not in your environment. As you walk with Him, doors you never imagined will open, and limits will be stretched beyond human expectations. Let go of societal limitations and embrace God’s plan. Those who know their God will do exploits.
BIBLE READINGS: Acts 17:24–28 PRAYER: Heavenly Father, I reject every
worldly limitation and embrace Your divine purpose for my life. Amen.
S’ÀWÁRÍ IPATÍ OLÓRUN FÚN O
IRUGBIN NAA
…ki won ki o le maa wá Oluwa, boya bi ọkànwọnbalefàsii,tiwọnsirii,biotilẹṣe pe kò jina si olukuluku wa: Ìse Awon Aposteli 17:27
Olorun ti fi ààlà si igbe aye re, kii se lati tè ̣é ̣ rì, bikose lati fa o mo’ra. Ipinnu Re fun aye re koja ohun ti ọ́le ri bayi. O le de ipele àtòkèwá nipa ifowosowopo pelu Re. Ipá otito re wa ninu Olorun, kiise ni agbegbe re. Bí o ti n báa rin, ilekun ti iwo kò láàyè pe yio sị́ ati ipele ti o ti d’opin ni a o fa koja oye enia. Jowo gbogbo ona ti aye ti f’oju tembelu re, ki o si tewogba ero Olórun. Awon ti o ba mo Olórun won yio se rere.
BIBELI KIKA: Ise Awon Aposteli 17:24- 28.
ADURA: Baba, mo ko gbogbo idiwo aye yii, mo gba erongba Re fun aye mi. Amin.