Do Not Praise Yourself

THE SEED

For we dare not make ourselves of the number or compare ourselves with some that commend themselves: but they are measuring themselves by themselves, comparing themselves among themselves, are not wise. 2 Corinthians 10:12.

Publicity and popularity are the aims of most celebrities in our present world. Young men and women are after fame and are known all over the world. This is one of the reasons
why social media has evolved in the last decade and has continued to thrive. If a good deed is done, the individual would like to tell everyone around that he or she was the one that did it and will like to be credited or appreciated for it. Blowing ones’ own trumpet as loud as possible is not a strange thing to some people. Apostle Paul was asking in 1 Corinthian 3:1, “do we begin to commend ourselves? or need we, as some others, epistles of commendation to you, or letters of commendation from you?” What do we think is the mind of God about this issue?
Jesus said, but when you do a charitable deed, do not let your left hand know what your right hand is doing, that your charitable deed may be in secret: and your Father who sees in secret,
will Himself reward you openly. Do not praise yourself. Let God appreciate and reward you. He will do it better than you can do it.

PRAYER

May God empower me to do all things for His praise. Amen

BIBLE READINGS: Matthew 6:3-5

MÁṢE YÍN ARA RE

IRÚGBÌN NÁÀ

“Nitoripe awa kò daṣa ati kà ara wa mọ́, tabi ati fi ara wa wé awọn miran ninu wọn ti ńyìn ara wọn; ṣugbọn awọn tikarawọn jẹ alailoye nigbati nwọn nfi ara wọn diwọn ara wọn, ti nwọn si nfi ara wọn wé ara wọn.” 2 Kor 10:12 BM

Ero awọn gbajumọ ode òni ni pé kí wọn polongo gbogbo iṣẹ wọn si gbogbo eniyan. Àwọn ọdọ l’ọkunrin l’obinrin ni won nlepa gbajumo ati iso di mímọ̀. Ara ìdí nìyí tí awon ohun
ibanisoro igbalode fi n dagbasoke ti wọn sì nlágbára si. Ti enikan ba ṣe ohun tí o dara, yíò fe lati sọ di mímọ̀fún gbogbo àwọn ti o wà layika rẹ̀ki o sí gbà ori’yin fún. Fifun fèrè ara ẹni ko jẹ àjèjì sí àwọn eniyan kan. Paulu Aposteli n beèrè ní ìwé Kọrinti keji 3:1 “Awa ha tún bẹ̀ẹ̀rẹ lati mã yìn ara wa bi? tabi awa ha nfẹ iwe iyìn sọdọ nyin, tabi lati ọdọ yin bi awọn ẹlomiran?” Bawo ni a ṣe ri èrò Ọlọrun nipa èyí si? Jesu wipe ‘Ṣugbọn nigbati iwọ ba nṣe itọrẹ ãnu rẹ, máṣe jẹ ki ọwọ́òsi rẹ ki o mọ̀ohun ti ọwọ́ọtún rẹ nṣe.’ Ki itọrẹ ãnu rẹ ki ọ le se itewogba, ma se yin ara rẹ. Sugbon jẹki Ọlọrun fún ọ ní ere pípé. Ọlọrun yio ṣe dara ju bi o ti le ṣe lo.

ÁDÙRÁ

Ki Ọlọrun ki o ràn mí lọwọ láti lè ṣe ohun gbogbo fún ìyìn orúkọ rẹ. Amin.

BIBELI KIKA: Matthew 6:3-5

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *