THE SEED
“Do not labor for the food which perishes, but for the food which endures to everlasting life.” — John 6:27 NKJV
Jesus teaches us to value eternal nourishment over temporary satisfaction. Physical food sustains the body briefly, but spiritual food sustains the soul forever. Many chase after what perishes while neglecting God’s Word, the true bread of life. Choose to feed your soul with what lasts — the Word and presence of God.
BIBLE READINGS: Matthew 4:1–4; John 6:22–35
PRAYER: Lord, give me grace to live by Your Word and not by bread alone. Amen.
O U ́ N J E Ṭ I ́ O ́ P E ́
IRUGBIN NAA
Ẹ má ṣe ṣiṣẹ́ fún oúnjẹ tí ń ṣègbé, ṣùgbọ́ n fún oúnjẹ tí ó wà títí di ayé àìnípẹ̀kun … Johanu 6:27
Jésù kó ̣ wa lati ná á ní ounje ayeraye dipo itelorun igba die. Ounje afojuri maa n yó ni lesekesesugbonounjetiÈṃ índièmímu laelae. Opo lo n lepa ohun ti o n segbe ti won a si kọ Oro Olorun, tii se ounje iye! Yan lati fún emi re ni ounje ti o pe- Oro ati iwalaaye Olórun.
BIBELI KIKA: Matthew 4:1-4
ADURA: Oluwa, fún mi ni oore ofe lati gbe ninu oro Re, kii se nipa akara nikan. Amin