THE SEED
“In every thing give thanks: for this is the will of God in Christ Jesus concerning you.” – 1 Thessalonians 5:18 (KJV)
Giving thanks is not optional — it is God’s will. True thanksgiving flows from a heart that trusts God even in uncomfortable situations. Praising Him in all seasons shifts our focus from the problem to the Promise Keeper. Praise is God’s delight, and when we offer it, He moves on our behalf. Gratitude disarms the enemy and strengthens faith. Thank Him in everything, and watch Him turn situations around for good.
BIBLE READINGS: Psalm 100:1–5 (KJV)
PRAYER: Lord, fill me with the spirit of thanksgiving in every situation. Let my praise bring glory to Your name and victory to my life. Amen.Tuesday, March 31, 2026
IDUPE NIGBAGBOGBO
IRUGBIN NAA
Ẹ mã dupẹ ninu ohun gbogbo: nitori eyi ni ifẹ Ọlọrun ninu Kristi Jesu fun nyin. 1 Tesalonika5:18
Idupe o kii se oun ti o le yan lati se, ife Olorun ni. Idupe otito ma nsun jade lati inu okan to gbekele Olorun paapa julo ninu awon ipo ti ko tura. Ti a ba nyin ni igba gbogbo, o ma mu oju wa kuro lori isoro lo si odo eni ti o nmu ileri se. inu didun Olorun ni iyin je, ti a ba si fi fun, o ma nse is wa. Idupe ma ngba agbara lowo ota, o si fi agbara fun igbagbo wa. Dupe lowo re ninu oun gbogbo, kio si ri bi yio se so oungbogbo di didara.
BIBELI KIKA: Orin Dafidi 100:1-5
ADURA: Oluwa, kun mi pelu emi idupe ninu gbogbo ipo. Jeki iyin mi fi ogo fun oruko re ati isegun si aye mi, Amin.