God Desires The Sacrifice Of Thanksgiving

THE SEED

“Let the giving of thanks be your sacrifice to God and give the Almighty all that you promised.” Psalm 50:14 GNT

Brethren, the desire of God our father is for us to be thankful to Him. To God, this is the most acceptable and greatest sacrifice to Him. It’s good to honour God with our substance, but this might be a tradition you have learned to do, not totally because you are personally thankful for receiving God’s blessings. In the case of the Israelites, God did acknowledge to have seen their burnt offerings which they were diligently bringing before Him, but God said that He didn’t see their thanksgiving! Thanksgiving is an expression of a grateful heart and it’s not bound to time, location, or situation. Whatever situation we find ourselves in must not dictate our attitude of thanksgiving to God; and unknown to many brethren, thanksgiving is a great weapon to win battles of life. If we’re habitual thanksgivers, God said that He will answer us in the days of trouble to save us. Winning life’s battles are not sometimes about thunderous prayer points, but trusting God in thanksgiving does open the most difficult doors.

PRAYER

Lord, I desire to be a habitual thanksgiver, let the spirit of thanksgiving fall afresh on me in Jesus’ name. Amen

BIBLE READINGS: Psalm 50:7-15

ỌLỌRUN ŃFẸ ẸBỌ ỌPẸ

IRÚGBÌN NÁÀ

“Ru ẹbọ-ọpẹ si Ọlọrun, ki o si san ẹjẹ́rẹ fun Ọga-ogo.” Orin Dafidi 50:14 BM

Ará, ìfẹ Ọlọrun ni wípé kí a máa dupẹ lọwọ rẹ̀. Fún Ọlorun èyí jẹ ohun ti o jẹ itẹwọgba julọ ati ẹbọ ti o ga jùlọ fun un. O dara ki a fi ohun ìní wa bọwọ fún Ọlọrun, sugbon eyi le já sí
ìṣẹ̀dálè ti a ti kọ̀wa ti kiiṣe nitoripe a fẹ fi tọkàntọkàn dupẹ fún ìbùkún tí a ri gba lọdọ Ọlọrun. Ọlọrun wipe oun ri ẹbọ sísun awọn ọmọ Israẹli, eyi ti wọn ṣe láì duro niwaju rẹ̀, sugbon Olorun wipe oun ko ri ẹbọ ọpẹ won! Ọpẹ je fifi im’oore lati inu ọkan hàn, eyi ko si ní ohunkóhun ṣe pẹlu àkókò, tabi ibi ti a wa, tabi idojukọ wa. Ipokipo ti a ba wa, ki a ma f’ọpẹ fún Ọlọrun. Ó jẹ́àimọ̀ fún àwọn ọmọ Ọlọrun kan wipe ọpẹ je ohun èlò lati jagun ṣẹgun ninu ayé. Ti a ba jẹ ẹniti o ndupẹ ni gbogbo ìgbà, Ọlọrun sọ wipe oun yo gba wa ni ọjọ ipọnju. Nigbamiran ìṣẹgun ninu ayé ko rọ̀mọ́awọn adura nlánlá, sugbon gbigbẹkẹle Ọlọrun ninu ọpẹ yíò ṣilẹkun ti o ṣòro ju fún wa.

ÁDÙRÁ

Oluwa, mo fẹ jẹ ọlọpẹ nigba gbogbo, jeki ẹmi ọpẹ bale mi ni akọtun l’oruko Jesu. Amin.

BIBELI KIKA: Orin Dafidi 50:7-15

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *