GOD IS A ‘COMPLETER’

THE SEED

“being confident of this very thing, that He who has begun a good work in you will complete it until the day of Jesus Christ;” Philippians 1: 6 (NKJV)

God will always finish what He has started. No matter how slow He appears to be moving. He does not give up on what He has set out to do. And He will always get what He wants, in the end. No matter how long it takes. Since this is so, how come this does not always appear to be true in our observation? Well, the truth is, there is more than one factor in the success of our lives. God has His part to play. And He can never fail. But we also have our part to play. And that is where our problems begin; for we are not as reliable, being human. We can cause delays by not submitting and walking in obedience. The children of Israel took 11 days to walk from Mount Sinai, just after they crossed the Red Sea, to KadeshBarnea: the border of the Promised Land. But crossing into the Promise land took 40 more years, because of disobedience and unbelief (Deut. 1: 2 & 3). We can delay matters unnecessarily by insisting on doing things our way and resisting the wisdom of God. Instead of acting this way, let us contemplate the faithfulness of God. He never fails. He will never fail!, so let us all make that conscious effort to trust His process in our lives and allow God to complete what He has started. The only person that can stop Him is you, submit to God afresh today. 

BIBLE READING: Deuteronomy 1:1-8

PRAYER: Heavenly Father, I submit myself anew to You today. Do what only You can do in Jesus name. Amen.

 

ỌLỌ́RUN ALÁṢE PÉ OHÙNGBOGBO

IRUGBIN NAA

“Ohun kan ni ó damiloju pe ẹnití ó ti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ réré nínú yín, yíò ṣe àṣepe rẹ̀ títí di ọjọ́ tí Jesu Kristi yóò dé. Fílípì 1: 6

Ọlọ́run máà npari ohun ti o ti bẹrẹ nigbagbogbo. Bó ti wù kí o dà bíi pé Ó ńi ilọ́ra tó. Kò ki njáwọ́ nínú ohun tó ti pinnu láti ṣe. Ati pe nigbagbogbo a máà ri àṣeyọrí ohun ti O fẹ, ni ipari. Bi o tí wù ki o pẹ to. Níwọ̀n bí èyí ti rí bẹ́ẹ̀, báwo ni èyí kò ṣe dàbí òtítọ́ nígbà gbogbo nínú àkíyèsí wa?. Ótítọ́ ni pé, ohun kan wà nínú àṣeyọrí ìgbésí ayé wa. Ọlọrun ni ipa tirẹ lati ṣe, ati pe ko lé kùnà. Ṣùgbọ́n àwa náà ni ipá tí wa láti ko; ibi ti awọn iṣoro wa tí bẹrẹ ni yi; nitori a ki i ṣe eniyan tí ó ṣeé fi ọkàn tán. A le fa idaduro nipasẹ kí kọ̀ àti láti rin ni ìgbọràn. Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì fi ọjọ́ mọ́kànlá rin láti Òkè Sínáì, lẹ́yìn tí wọ́n la Òkun Pupa kọjá, títì de Kadeṣi-Barnea; ààlà Ilẹ̀ Ìlérí. Ṣùgbọ́n ríré kọjá sí Ilẹ̀ Ìlérí gba ogójì ọdún síi! Nitori àìgbọràn ati aigbagbọ Deuteronomi 1; 2-3. A lé fa idaduro làì ní di, nipa fífi dandan lé, lati ṣé àwọn nkan ní ọ̀nà tó wù wá, kí a sí kọ ọgbọ̀n Ọlọ́run. Dípò tí a ó fi ṣe bẹ́ẹ̀, ẹ jẹ́ kí a ronú lórí Ìjolòtitọ́ sí Ọlọ́run. Ki i kuna. Oun ko lé kuna! nitori naa jẹ ki gbogbo wa ṣe igbiyanju ti o yio di mí mọ̀ lati gbẹkẹle ilana Rẹ ninu igbesi aiye wa, lati gba Ọlọrun laaye ki ó pari ohun ti O bẹrẹ. Ẹnikan ṣoṣo ti o le da a duro, ni iwọ, tẹriba fun Ọlọrun lọtún loni

BIBELI KIKA: Deuteronomi 1: 1-8.

ADURA: Baba ọrun mo fi ara mi silẹ fun ọ ni ọtún loni. Ṣe ohun ti ìwọ nikan le ṣé, ni orúkọ Jesu. amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *