GOD IS MY REFUGE

THE SEED

“He raiseth up the poor out of the dust, and lifteth up the beggar from the dunghill, to set them among princes, and to make them inherit the throne of glory: for the pillars of the earth are the Lord’s, and he hath set the world upon them.” 1 Samuel 2:8

What God can’t do doesn’t exist, so when He begins to lift you, no one can bring you down. When human beings promote you, they never want to put you on the same level as themselves. Joseph was promoted to be in charge of everything in Potiphar’s house, but still remained a slave. That is the way of man, they give you with one hand and collect with another hand. The same promoter of Joseph was the same man after knowing the truth still end up throwing him into prison, hosanna today, crucify tomorrow. The story of Joseph is not complete without the promotion of God and it’s only because he made God the most High,His refuge, make Him your refuge today and see the glory of God. The Almighty God took David – who was a shepherd boy, made him a king and kept on promoting him until he became the father of the King of Kings.

BIBLE READING: Revelation 22 : 16

PRAYER: Holy Spirit help me to be humble, so that God can promote me.

ỌLỌRUN NI ÀÁBO MÍ

IRUGBIN NAA

“O gbe talaka lati inu erupẹ wá, O gbe alàgbe soke lati ori ààtàn wá láti kó wọn jọ pẹlu awọn ọmọ-alade, láti mú wọn jogun itẹ ogo: nitori ọwọn ayé tí Óluwa ní o sí tí gbé ayé ka orí wọn.” 1 Samueli 2:8

 

Ohun ti Ọlọrun ko le ṣe ko si, nitorina nigbati O ba bẹrẹ lati gbe ọ soke, ko si ẹnikan ti o le gbe ọ walẹ. Nigbati awọn eniyan ba gbe ọ ga, wọn ko fẹ lati fi ọ si ipele kanna bi ara wọn. Wọ́n gbé Jósẹ́fù ga gẹ́gẹ́ bí alábòójútó ohun gbogbo ní ilé Pọ́tífárì ṣùgbọ́n ó ṣì papa jẹ́ ẹrú. Èyí jẹ́ nipa ọna eniyan, wọn o fun ọ ni ohun kán pẹlú ọwọ kan, wọn a sì gba a pada pẹlu ọwọ miiran. Ẹni kan naa tí o gbé Josẹfu ga, sí ni ọkunrin kan naa lẹhin ti o ti mọ otitọ, ni o tun sọ ọ sinu tubu, Hosanna loni, kàn mọ agbelebu ni ọla. Igbega ti Ọlọrun jẹ pátá pátá nípa ti itan Joseph, ní torí wípé o fi ọ̀gá ògo julọ ṣe àbo rẹ; fí i ṣe ibi aabo rẹ loni ki o si ri ogo Ọlọrun. Ọlọ́run Olódùmarè mú Dáfídì tí ó jẹ́ ọdọ ọmọkùnrin olùṣọ́-àgùntàn, ó fi í jọba, ó sì ń gbé e ga títí ó fi di baba fún ọba àwọn ọba.

BIBELI KIKA: Ìfihàn 22:16

ADURA: Ẹ̀mí Mímọ́ ràn mí lọ́wọ́ láti jẹ́ onírẹ̀lẹ̀ kí Ọlọ́run lè gbé mi ga.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *