GOD IS OMNIPRESENT

THE SEED
“For thus saith the high and lofty One that inhabiteth eternity, whose name is Holy; I dwell in the high and holy place, with him also that is of a contrite and humble spirit, to revive the spirit of the humble, and to revive the heart of the contrite one.

God is omnipresent. Has it ever dawned on you that God never has to go anywhere? God is everywhere. Sometimes we get the idea that God is at worship centres. One thing you need to know is that God is everywhere. There is no place that God is not. There is not a movement but He sees it, a motive but He knows it, nor a murmur but He hears it. Death, distanceor darkness cannot hide you from God. It’s a thrilling or a threatening thought depending on your relationship with God. When you are through a turbulence, which seems like a dark period in your journey through life and you have blossming relationship with God, it is not darkness to God. When things don’t make sense and you can’t understand anything; just recognize that God is present. While you can’t see through that darkness, He can. When you learn how to apply the presence of the Lord, God will become a bright, living reality to you, seeing you through.

BIBLE READING: Isaiah 57

PRAYER: See through every void and dark places of my life and foundation O Lord and restore your light in it Amen

 

 OLORUN WA NI IBI GBOGBO

IRUGBIN NAA

“Nitori bayi li eni giga ati eniti a gbega soke so, ti n gbe aiyeraye, oruko eniti nje mimo, Emi ngbe ibi giga ati mimo, ati inu eniti oni emi irobinuje on irele pelu, lati mu emi awon onirele soji, ati lati mu okan awon onirobinuje soji.”    Isaiah 57:15

Olorun wa ni ibi gbogbo. Nje o tile mo wipe Olorun ko nilo lati lo si ibikibi? Olorun wa ni ibi gbogbo. Nigba miran, a maa nwoye wipe ile ijosin ni Olorun maa n wa. Ohun kan ti o gbodo mo ni wipe, Olorun wa ni ibi gbogbo, ko si ibi ti Olorun ko si, bi ko tile rin, sugbon o rii, erongba, O mo o, ikunsinu, o gbo won. Iku, ona jinjin, tabi okunkun ko lee mu o pamo kuro niwaju Olorun. Ero okan ti nmu inu eni dun tabi ti n mu iberu wa, gege bii ibasepo re pelu Olorun. Nigba ti o ba wa ninu okunkun, ki ise okunkun lodo Olorun. Nigba ti nkan ba dojuru, ti oye ohunkohun ko si ye o mo, iwo saa ti ni lokan wipe Olorun wa ni ibe, nigbati iwo ko le riran ninu okunkun, on riran. Nigba ti o ba ti mo bi a ti nse amulo iwalaaye Olorun, Olorun yio di imole ati iye fun o, yio si ran o lowo.

BIBELI KIKA: Isaiah 57

ADURA: Wo inu gbogbo ibi ti sofo ti o si sokunkun ninu aye mi ati ipinle mi, Oluwa, ki o si mu ki imole re pada si inu re. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *