GOD REVEALS MYSTERIES

GOD REVEALS MYSTERIES

THE SEED

“…Your God is the greatest of all gods, the Lord over kings, and the One who reveals mysteries. I know this because you have been able to explain this mystery.” — Daniel 2:47 GNB

God is not silent about the mysteries of life—He is the Revealer of Secrets. He revealed to Daniel what no magician, sorcerer, or wise man could interpret. Yet, many Christians live as if God cannot or will not speak to them. The truth is: God knows everything and is willing to reveal what you need to know when you ask in faith. If you are His child, He delights in guiding you. Trust Him for insight, wisdom, and direction. The same God who revealed secrets to Daniel is still speaking today.

BIBLEREADINGS: Daniel2:14–30 PRAYER: Heavenly Father, thank You

because You are the Revealer of mysteries. Give me understanding and direction whenever I ask. Amen.

ỌLỌ́RUN MÁA N FI OHUN IJINLẸ HAN

IRUGBIN NAA

“Ọba da Dáníélị̀ lóhùn, o si wípé Lootọ ni, pé Ọlọrun yín li Ọlór ̣ un àwọn ọlór ̣ un àti Olúwa àwọn ọba, àti olufihan ohun gbogbo àṣírí, nítorí tí ìwọ le fí àṣírí yí han.” DÁNÍÉḶ Ì 2:47

Ọlọ́run kò dákẹ́ nípa àwọn ohun ìjìnlẹ̀ ayé —Òun ni Olùfihan àwọn Àṣírí. Ó fihan fun Dáníélị̀ ́ ohun tí kò sí pidánpidán, oṣó, tàbí amòye kan tó lè túmọ̀ rẹ̀. Síbẹ̀, ọ̀ pọ̀ Kristẹni ń gbé bí ẹni pé Ọlọ́run kò lè bá wọn sọ̀rọ̀ tàbí kò tilẹ ní, bá wọn sọ̀rọ̀. Òótọ́ ibẹ̀ ni pé: Ọlọ́ run mọ ohun gbogbo, ó sì múra tán láti fi ohuntíóyẹkiómọ̀ hàn,nígbàtiobábéèrè nínú ìgbàgbọ́. Ti ìwọ ba jẹ ọmọ Rẹ̀, inu Rẹ̀ dun lati dari rẹ. Gbẹkẹ rẹ le fun oye, ọgbọn, ati itọsọna. Ọlọ́run kan naa ti o fí àṣírí hàn fún Danieli si n sọ̀rọ̀ titi dí oni.

BIBELI KIKA: Dáníẹ́lì 2:14–30. ADURA: Baba wa Ọrun, mo dupẹ nitori

iwọ ni Olufihan awọn ohun ijinlẹ. Fun mi ni oye ati itọsọna nigbakugba ti mo ba beere. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *