God’s Heritage

GOD’S HERITAGE
THE SEED
The earth is the LORD’s, and the fullness thereof; the world, and they that dwell therein. Psalm 24:1

God is the owner of everything, and we are given a portion of what He owns. We enjoy both receiving and dispensing from His riches. The first verse of the Bible lists the earth, things on the earth, the world, and the living things on the earth as the four fundamental things that still belong to God. One could infer from these four items that the Bible indicates that Jesus Christ is the true owner of everything we possess, including ourselves (Colossians 1:16-17). Because of Jesus, everything exists (Hebrews 2:10). What Jesus intended when He created anything will determine how to use it. Knowing the root of everything teaches us how to use everything. You can never get beyond God, no matter how deep you delve into God’s riches, wisdom, or knowledge. More strong than God cannot be explained. Nothing is impossible for God and nothing is superior to God. Nothing can be given to God that isn’t already His. Everything is created by him, through him, and with His glory in mind. Dearly Beloved, it is crucial to understand that your possessions, wealth, and intelligence cannot save you; in fact, they all belong to God in any case!

PRAYER
Teach me to serve you with my substance and to surrender all I have for your use.

BIBLE READINGS: Psalm 24

OHUN ÌNÍ ỌLỌRUN

IRUGBIN NAA 
Ti oluwa ni ilẹ̀ atí ẹkùn rẹ, ayé ati àwọn ti o tẹ̀dó sínú rẹ. Psalmu 24:1

Ọlọrun ní o ni ohun gbogbo, a sì fún wá ni apakan nínú ohun tí o ní. A ngbadun gbigba ati lilo ninu ọrọ̀ rẹ. Ẹsẹ akọkọ ninu bibeli tí a kà tọka sí ilẹ, ayé àti ohun gbogbo alààyè tí mbẹ lóri ilẹ; bi ohun mẹrin akọkọ tí o jẹ tí Ọlọrun. A lè mú nínú ohun mẹrin ti bíbélì tọka sí pé Jésù ni ẹni otitọ tí o ní ohun gbogbo ti a ni, titi kán àwa tikara wa (Kolose 1:16-17). Nitori Kristi ní ohun gbogbo ṣe wà (Heberu 2:10). Ohun tí Jésù ní lọkàn nigbati O da ohun kan, yíó tọka sí bí a ti ṣe ló awọn ohun tí O dá. Ìmọ ibẹrẹ ohun gbogbo yíó kọ wa bí a o ti ṣe ló ohun gbogbo. O kó lè t’ayọ Ọlọrun, bí o ti wù kí a ni jinlẹ̀ to ninu ọrọ̀, ọgbọn, tàbí ìmọ. Ko sí ohun tí o ṣòro fún Ọlọrun tàbí ohùn tí o ga jù Ọlọrun lọ. Kò sí ohun tí a lè fún Ọlọrun ti kò jẹ pé Òun ní o ní. Ohun gbogbo ní Ọlọrun da, tí a sì dá lati ipasẹ rẹ, ati pelu ogo Rẹ. Olufẹ ọwọn, o pọn dandan lati ni òye pé àwọn ohun tí a ní, ọrọ̀, ati ìmọ ijinlẹ kò lè gba wá: gbogbo rẹ̀ ni o jẹ́ tí Ọlọrun.

ADURA
Kọ mi lati sìn Ọ pẹlú ohun ìní mi ati lati fún Ọ ní ohun tí mo ní fún ìlò Rẹ̀.

BIBELI KIKA: Psalmu 24

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *