GUARD AGAINST DECEPTION

GUARD AGAINST DECEPTION
THE SEED
“Then I saw three unclean spirits that looked like frogs… out of the mouth of the dragon, the beast, and the false prophet.” — Revelation 16:13 GNB
Deception is increasing in our world. False teachings, twisted truths, and misinformation spread quickly. Anything that is not aligned with the Word of God is deception. Believers must test every message — from pulpits, media, and conversations — against the Word and the Spirit of God. Accepting a lie can lead us away from God’s plan. Staying rooted in truth keeps us safe.
BIBLE READINGS: 1John4:1–6
PRAYER: Heavenly Father, deliver me from the deception of these end times. Amen.

PA ỌKÀN RẸ MỌ́ KÍ A MÁ BA TÀN Ọ́  JẸ
IRUGBIN NAA
“Mosìríàwọnẹ̀míàìmọ́ mẹ́tabíọ̀pọ̀lọ́,wọ́n ti ẹnu dragoni náà àti ẹnu ẹranko náà àti ẹnu wòlíì èké náà jáde wá.” ÌFIHÀN 16:13
Ẹtan n pọ si nínú ayé yii. Àwọn ẹ̀kọ́ èké, òtítọ́ tíayipadasiirọ,àtiọ̀rọ̀ òdìntànkálẹ̀
kíákíá. Ohunkohun ti ko ni ibamu pẹlu Ọrọ Ọlọrun jẹ ẹtan. Awọn onigbagbọ gbọdọ dan gbogbo ìwàásù wo – eyi ti o wa lati orí àga ìwàásù, tabi orí ẹ̀rọ ayelujara, ati awọn ibara-ẹnisọrọ – ti o lodi si Ọrọ ati Ẹmí Ọlọrun. Gbigba irọ́ le mu wa kuro ninu eto Ọlọrun. Dídúró pèlụ́ ifẹsẹmúlẹ nínú òtítọ pa wá mọ́.

BIBELI KIKA: 1 Jòhánù 4:1–6.
ADURA: Baba wa ọrun, gba mi lọwọ ẹtan ti awọn akoko ìkẹyìn wọnyi. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *