THE SEED
“A good tree cannot produce bad fruit, and a bad tree cannot produce good fruit.” — Matthew 7:18 NLT
Your thoughts shape your reality. True faith is not just agreeing with the Word of God but believing it deep within your heart. What you truly believe on the inside is what manifests outwardly in your life. Your mind is the battlefield where victory begins. When your heart is aligned with God’s Word, your life will reflect His truth. Guarding your thoughts means intentionally filtering what enters your heart and allowing only His promises to take root. Meditate on God’s promises until they take root in your spirit. A good tree cannot produce bad fruit—when your inner man is filled with faith, your life will bear fruit that glorifies God.
BIBLE READINGS: Proverbs 4:20–27
PRAYER: Heavenly Father, fill my heart with Your Word and help me produce good fruit. Amen.
SỌ̣́ ÈRÒ ỌKAǸ RẸ
IRUGBIN NAA
igi rere kò le so èso búburú, bẹẹ ni igi búburú kò lè so èso rere. Matiu 7:18
Ero re nii n s’eto bí iwo yoo ti je. Igbagbo otito kii se gbigba oro Olorun nikan bikose gbigbagbo ninu re pelu okan re. Ohun ti o gbagbo nitooto ninu re ni o n f’ara han ninu aye re. Okan re ni oju ogun ibi ti isegun ti bere. Ti okan re ba wa ni ibamu pelu oro Olórun, aye re a fi otito Re han. Sị ́ṣọ́ ero okan re tumo si mímọ̀ọ́mọ̀ sa awon ohun ti o n wo okan re ati gbigba ileri Re nikan laaye lati ni gbongbo. Se asaro lori ileri Olorun titi ti won yio fi ni gbongbo ninu emi re. Igi rere kò le so eso buburu- nigbati o ba kun fun igbagbo, aye re yio so eso ti yio fiyin f’Olorun.
BIBELI KIKA: Iwe Owe 4:20-27
ADURA: Baba mi Orun, kun okan mi pelu Oro Re ki o si ran mi lowo lati so èso rere. Amin.