GUARD YOUR TONGUE

THE SEED

“Let no corrupt communication proceed out of your mouth, but that which is good to the use of edifying, that it may minister grace unto the hearers.” — Ephesians 4:29 KJV

Many people desire to be heard, but as believers, our speech carries spiritual weight. Apostle Paul reminds us to guard our words carefully. The tongue has power, and with it comes great responsibility. Our speech reflects the state of our hearts and spiritual maturity. Redeemed speech can only come through the work of Christ in us. When we yield our tongue to the Holy Spirit, our words become channels of grace, healing, and edification. Ask the Lord to help you control your speech so that it glorifies Him always.

BIBLE READINGS: James 3:1–12

PRAYER: O Lord, put a lock on my lips that I may not speak evil words. Amen.

 

PAAHỌN RẸ MỌ́

IRUGBIN NAA

“Ẹmáṣejẹ́kíọ̀rọ̀idibajẹkantíẹnuyìnjáde, ṣùgbọ́n irú eyítí o dára fún ẹ̀kọ́, kí ó lé máà fí ore-ọfẹ fún àwọn tí ń gbọ́.” ÉFÉSÙ 4:29.

Ọ̀pọ̀ènìyànlómáańfẹ́kíwọ́ngbọ́ọ̀rọ̀wọn, ṣùgbóṇgẹ́gẹ́bíonígbàgbọ́,ọ̀rọ̀ẹnuwamáa kun fun ẹ̀mí. Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù rán wa létí pé ká ṣọ́ ọ̀rọ̀ wa . Ahọn ni agbara eyi ti o je ojuse nlafunwa.Ọ̀rọ̀ẹnuwamaanfiirúipòtí ọkàn wa wà hàn àti ìdàgbàsókè wa nínú ẹmí. Ọ̀ rọ̀ eni iràpadà maa n wá nípasẹ̀ iṣẹ́ Kristi nínú wa. Nigba ti a ba fi ahọn wa fun Ẹmi Mimọ, awọn ọrọ wa yíò di atọ́ kù n fún ore- ọfẹ, iwosan, ati imuduro. Beere lọwọ Oluwa lati ran ọ lọwọ lati ṣakoso ọrọ rẹ, ki o le maa ṣogo fun Un nigbagbogbo.

BIBELI KIKA: Jákọ́ bù 3:1–12.
ADURA: Oluwa, fi ẹṣọ si ète mi ki emi ki o má ba a sọ ọrọ buburu. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *