HE’S MY KING

THE SEED
“The earth is the Lord’s, and the fullness thereof; the world and they that dwell therein.” Psalm 24 : 1

In the olden days, kings are seen as supreme beings or leaders and the owners of the land. And everyone concede this power to them. Until when I read in the Bible how king David praised the Almighty God in his lifetime. The Bible passage we read makes it clear that everything on earth, under the earth belongs to God. That makes me to conclude that everything we have, belongs to God; All things were made by him and without him was not anything made that was made. He is my king, he owns my creation, he decided to make us who we are with all the beautiful things of life and abundant provision to enjoy life. What do you have that has not been given; your ability, your wisdom, your wealth, your knowledge, your success and all you can think of was given by Him that owns everything. Paul said I am what I am by the grace of of God. 1 Corinthians 15:10. The peace you are enjoying can only be found in God, He is my king.

BIBLE READING: Acts 17:28

PRAYER: Lord Jesus Christ I confess you as my King, Lord and Saviour.

  ÒUN NI ỌBA MI

IRUGBIN NAA

“Ti Oluwa ni ilẹ ati ẹ̀kún rẹ́ ayé àti àwọn tí o tẹ̀do sínú rẹ.” Psalmu 24:1

 

Ni igba atijọ a rí awọn ọ́ba bi awọn eeyan giga julọ tabi awọn oludari ati awọn ti o ní Ilẹ naa.  Gbogbo ènìyàn sì fi agbára yìí lé wọn lọ́wọ́: Títí di ìgbà tí mo rí nínú Bíbélì bí ọba Dáfídì ti nyin Ọlọ́run Olódùmarè. Ibi ti a kà nínú Bibeli jẹ ki o ye wa pe ohun gbogbo ti o wa lori lẹ ayé jẹ ti Ọlọrun. Èyí mú mí pinnu pe ohun gbogbo ti a ni, jẹ ti Ọlọrun. Nipasẹ̀ rẹ̀ li a ti da ohun gbogbo, laisi rẹ̀ kò sí ohun tí a da  ti o jẹ́ di da. Oun ni Ọba mi, oun ni iṣẹda mi, o pinnu lati da wa pẹlu gbogbo awọn ohun tó lẹwa nínú aye ati ipese lọpọlọpọ lati gbadun igbesi aye wa. Kini ẹ ni ti ko jẹ pé a fi fun yín; ipá rẹ, ọgbọn rẹ, ọrọ̀ rẹ, imọ rẹ, aṣeyọri rẹ ati gbogbo ohun ti o le ronu nipa rẹ ni a fun wa ni nipasẹ ẹniti o ni ohun gbogbo. Paulu wipe Emi jẹ ohun ti mo jẹ̀ nipa ore-ọfẹ Ọ́lorun.1Kor 15:10.  Àlàáfíà ti o  ngbadun ni le ri ninu Ọlọrun nikan. Òun ni Ọba mi.

BIBELI KIKA: Iṣe Awon Aposteli  17:28

ADURA: Jesu Kristi Oluwa mo jẹ̀wọ́ rẹ gẹgẹ bi ọba mi, Oluwa ati Olugbala.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *