House On The Rock

THE SEED
Therefore whosoever heareth these sayings of mine, and doeth them, I will liken him unto a wise man, which built his house upon a rock:” Matthew 7:24

God has a way of measuring who is wise and who is not wise; His criterion is based on who is obedient to his Word. Those who are doing his Word are referred to as wise and those who are not doing his Word are referred to as simple or foolish. Doing the Word has good reward but disobedience to his Word has just punishment. The one who hears the Word and does it is building his/her life on the rock and the one who hears the Word and ignores it is building his/her life on the sand. Both builders are tested by the rain, flood, and wind. The one who built on the rock stood the test; in fact it was not shaken by the rain, flood, and the wind. The one who built on the sand fell and great was the fall. Those who take advantage of the grace of God to do the Word of God are prepared to withstand the pressures of life but those who reject grace to please themselves are preparing themselves to fail in life.

BIBLE READING: Matthew 7

PRAYER: I speak into my life, stand firm on the solid Rock of Ages (Jesus Christ) Amen

ILE ORI APATA

IRUGBIN NAA
“Nitorina ẹnikẹni ti o ba gbọ orọ temi wọnyi, ti o ba si ṣe wọn, emi o fi wé ọlọgbon ẹniyan kan, ti o ko ile re sori apata:” Matteu 7:24

Ọlorun mo onà lati se oduwon ẹni tí ó gbon atí eni ti kò gbon; oduwon re wa Lori eni ti o gboran si Oro re. Awon ti o se ife re ni a Ka si ọlọgbon bee sini awon ti kò se ni a Kasi asiwere. Sise ife re ni ere pupo ṣugbọn aigbọran si Ọrọ maa n fa ijiya. Ẹni tí ó gbo oro náà, tí ó sì ṣe, ó ń ko emí re lé orí àpáta, ẹni tí ó bá sì gbo oro náà tí kò sì kọbi ara sí, ó ń gbé emí re lé orí iyanrìn. Òjò, ìkún omi, àti efúùfù ti dán àwọn omolé méjèèjì wò. Ẹniti o ko lori apata duro ni idanwo; Ní ti tòóto òjò, ìkún omi, àti efúùfù kò mì i.Ẹni tí ó ko sórí iyanrìn ṣubú lule, ìṣubú ńlá sì ni. Awọn ti o lo anfani oore-ọfẹ Ọlọrun lati ṣe Ọrọ Ọlọrun ti mura lati koju awọn wahala ti igbesi aye ṣugbọn awọn ti o kọ oore-ọfẹ lati ṣe itẹlọrun ara wọn setan ara wọn lati kuna ninu igbesi aye.

BIBELI KIKA: MATIU 7

ADURA: Mo soro sinu aye mi, duro ṣinṣin lori Apata ti o duro le (Jesu Kristi) Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *