I’M GRATEFUL FOR YOUR PEACE

em>THE SEED

”And the peace of God, which surpasses all understanding, will guard your hearts and your minds in Christ Jesus.“ Philippians 4:7

It has been a great privilege to travel this year with the peace of God in our lives. Having God’s peace does not mean that we don’t pass through challenges; it is the feeling we have that God is with us and He’s got our back. Reflecting on all the Lord’s goodness from the beginning of this year to now, if we are faithful our confession should be, ‘Lord I’m grateful’. The peace that Apostle Paul prayed for in our opening scripture is such that can not be understood by the flesh, it is the inner peace that is divine. It is for guidance to put our hearts and minds at ease in chaotic situations which I believe we have all had a taste of in the year.

Beloved, in a world filled with chaos, God’s peace is our refuge and fortress; it is just right to take a moment to thank God for the peace we have enjoyed from Him, especially in times of trouble. His peace surpasses all understanding, and it guards our hearts and minds. Be grateful for His calming presence that always assures us that all shall be well. 

BIBLE READINGS:  Psalm 105:1-3

PRAYER: God of peace, I wholeheartedly thank you for your peace upon my life, family and community, in Jesus’ name. Amen 

 

MO DUPE FUN ALAFIA RE

IRUGBIN NAA

Àti àlàáfíà Ọlọrun, tí ó jù ìmọ̀ràn gbogbo lọ, yió ṣọ́ ọkàn àti èrò yín nínú Kristi Jésù. Filipi 4:7

Ó jẹ àǹfààní nla lati rin irin-ajo ni ọdun yii pẹlu àlàáfíà ti Ọlọrun nínú igbesi aye wa. Níní àlàáfíà Ọlọ́run  ko tumọ  si pe a ko ní kọjá nínú awọn wàhálà: o jẹ ìmọ̀lára ti a ni pe Ọlọ́run  wa pẹlu wa ati  o sí ni itẹle wa. Nípa ironu lori gbogbo oore Oluwa lati ibẹrẹ ọdun yii di isinsinyi ti a ba jẹ olotitọ ijẹwọ wa yẹ ki o  jẹ Oluwa mo dupe lọwọ Rẹ. Àlàáfíà ti aposteli Paulu gbadura fun ninu ibẹrẹ iwe-mimọ wa, jẹ́ iru èyí  tí ẹran-ara ko le loye re, irú àlàáfíà yi wá láti isalẹ inú, irú àwọn èyí tí ó tí òkè wa. Olùfẹ́ nínú aye tí o kun fún rúdurùdu, àlàáfíà Ọlọrun ni ibi ààbò àti òdì wa. O yẹ ki a wa ìṣẹ́jú kan lati dúpẹ́ èyí  ti ati jẹ́ didun rẹ̀  láti ọ̀dọ̀ Rẹ̀, pàtàkì jù lọ ni ìgbà iponju. Àlàáfíà Rẹ̀ jù gbogbo òye, o sí ntọ àwọn ọkàn àti èrò wa. Dúpẹ́ fún iwàláàyè Rẹ tí tí ó tú ní lára tí ó sí  nfun wa in ìdánilójú pé óhun gbogbo yíò dara.

BIBELI KIKA: Psalmu 105:1-3

ADURA: Ọlọ́run alaafia, mo dupẹ lọwọ Rẹ tọkàntọkàn fun alaafia rẹ lori idile mi, ati agbegbe mi ni orúkọ Jesu amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *