In The Time Of Trouble

THE SEED
“And call upon me in the day of trouble: I will deliver thee, and thou shall Glorify me.” Psalm 50:15(KJV)

When trouble blows its whistle at us, as a Christian. we should call upon God. The believer, though is not free from trouble but he is assured of the presence and help of God when facing difficulties. God knows there will be days of trouble and He that allowed it like in the time of Job knows how to deliver his children for his name to be glorified. God will not allow any challenges greater than our capability to come our way. He will always provide an escape route. The Bible says” He shall deliver thee in six troubles yea; in seven there shall be no evil touch thee. King David acknowledged God’s promise of deliverance in times of difficulties. No matter the trouble you find yourself lean on the promises of God that are yea and Amen! keep this in mind that, Jesus is bigger than your troubles, trust Him, believe in him and He will never let you down. Praise God!

BIBLE READING: Psalm 34:4-8

PRAYER: Lord, I pray that you never leave or forsake me in the face of challenges in Jesus name Amen.

NI ASIKO EWU

IRUGBIN NAA
“Ki o si pè mi li ọjọ ipọnju: Emi o gbà ọ, iwọ o si yìn mi logo.” Sáàmù 50:15

Nígbà tí wàhálà bá dojuko wa, gẹ́gẹ́ bí Kristẹni kí a ké pe Ọlọ́run. Gege bi Onigbagbọ,ko le sai si ìṣòro sugbon a ti fi dawa loju pe ifarahan Ọlorun yio ran wa lowọ nígbà ti a ba n dojuko isoro. Ọlọ́run mo pé ọjọ́ wàhálà yóò wà, Ẹni tí ó sì fàyè gbà á gẹ́gẹ́ bí ìgbà ayé Jóòbù mo bí yi o ti dá àwọn ọmọ re nídè kí orúkọ òun lè di ògo. Ọlọ́run kò ní jẹ́ kí àwọn ìpèníjà èyíkéyìí tó ju agbára wa lọ láti wá bá wa. Oun yoo pese ọna abayo nigbagbogbo. Bíbélì sọ pé: “Yóo gbà ọ́ nínú wàhálà mẹ́fà, bẹ́e ni, nínú méje, ibi kan kì yóò fọwọ́ kan ọ́.” Dáfídì Ọba jẹ́wọ́ ìlérí ìdáǹdè Ọlọ́run ní àkókò ìṣòro. Beeni ati Amin! Ni eyi lokan pe, Jesu tobi ju idamu re lo. Gbekele, gbagbo ninu re ko ni ja yin kule laelae. Yin Olorun!

BIBELI KIKA: Sáàmù 34:4-8

ADURA: Oluwa, mo gbadura pe ki o ma fi mi sile tàbí komi síle ni oju awon ipenija loruko Jesu Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *