THE SEED
“For he said unto him, Come out of the man, thou unclean spirit.” Mark 5: 8 KJV
A deliverer is one who set free or saves another from a difficult situation. Jesus is the great deliverer from sin, bondage and the great deliverer from death. Jesus travelled with his twelve disciples to the other side of the sea into the country of the Gadarenes there he met a demon-possessed man with legion of wicked spirits rushing out from the rocky tombs to meet Jesus. He was naked, filthy and unkempt, a terror to himself and others. He lived among the dead in the burial tombs, he had no rest, no sleep, no relaxation the evil spirit was in him crying making him uncomfortable.
Imagine the pain and sorrow his father, mother and relatives must have been going through, no man could bring him into soberness, sanity or bring him under control or had solutions to his problems. The description of this man is one of the most pitiful and wretched in the bible but when he met with Jesus the great deliverer immediately he regained his freedom and became normal as if nothing ever happened to him. Is there any dark tunnel in your life? it can never be more than the suffering of this man that has been in bondage for some time. Run unto Jesus the great deliverer, He is 100% ready to set you free and whenever Jesus the only Son of God set you free you are free indeed.
BIBLE READING: Mark 5: 1 – 8.
PRAYER: Heavenly Father, set me free from all troubles and difficulties in Jesus name. Amen.
JESU OLUDANDE NLA
IRUGBIN NAA
“Nitoriti o wi fun u pe, Jade kuro ninu ọkunrin na, iwọ ẹmi aimo.” Marku 5:8
Olùdáǹdè je ẹni tí ó tunisile tàbí tí ó gba ẹlòmíràn là kúrò nínú isoro.Jesu ni Olugbala nla ti n gbani lọwọ ẹṣẹ, igbekun ati Olugbala nla lọwọ iku. Jésù àti àwọn ọmọ eyìn re méjìlá rìnrìn àjò lọ sí òdìkejì òkun sí ile àwọn ará Gádárà, nibe ló pàdé ọkùnrin kan tó ní emi Esu tó ní ẹgbe ọmọ ogun emí búburú, tó ń sáré jáde látinú ibojì olókùúta láti wá bá Jésù. Ó wà ní ìhòòhò, o doti, o je eru fún ara re àti àwọn ẹlòmíràn. Ó ń gbé láàrín àwọn òkú nínú ibojì ìsìnkú, kò ní ìsinmi, kò sùn, kò sí ìsinmi, emí búburú wà nínú re tí ń sọkún, to si n fara ni. Fojú inú wo ìrora àti ìbànúje ti bàbá re, ìyá re àti àwọn molebí re yio ti dojuko ti ko si seni tó lè tuu Lara tàbí tan gbogbo isoro re. Ipo ti arakunrin yi wa je eyi ti o se ni laanu julo ninu bibeli ṣugbọn nigbati o pade JESU OLUDANDE NLA julo, lẹsẹkẹsẹ o gba ominira rẹ pada o si dabi ẹnipe ko si ohun ti o ṣẹlẹ si i.Nje isoro nla bayi wa ninu aye rẹ? Kò lè ju ìjìyà ọkùnrin yìí tí ó ti wà nínú ìdè fún ìgbà díe lọ. Sa to Jesu Olugbala nla, O ti mura lati sọ ọ di ominira ati pe nigbakugba ti Jesu Ọmọ Ọlọrun kan ṣoṣo ba so o di ominira, Iwo yio gba Ominira nitooto.
BIBELI KIKA: Máàkù 5:1-8
ADURA: Baba ọrun, tu mi silẹ ninu gbogbo isoro ati wahala ni orukọ Jesu. Amin.