THE SEED
“Come unto me, all ye that labour and are heavy laden, and I will give you rest.” – Matthew 11:28 (KJV)
Some people achieve success with little effort, while others struggle despite hard work. In both cases, Jesus remains the only sure catalyst who makes the journey easier. His presence brings peace, favour, mercy, and fulfilment.
He invites us to come to Him and find rest in every struggle. No matter how trivial or complex the situation, if we let Him lead, we will not be stranded. His guidance turns rough roads into smooth paths and hopeless battles into victories.
BIBLE READINGS: John 14:1–6 (KJV)
PRAYER: Jesus, open my inner eyes to see Your leading through Your Word today. Amen.
JESU, ABANISE KAN SOSO
IRUGBIN NAA
Ẹ wá sọdọ mi gbogbo ẹnyin ti nṣiṣẹ́, ti a si di ẹrù wuwo le lori, emi o si fi isimi fun nyin. Matteu 11:28
Igbiyanju die ni awon kan fi nse aseyori, sugbon awon miran ma ntiraka pelu ise asekara. Larin iru awon eniyan mejeeji yi, Jesu je abanise kan soso ti o le je ki irinajo naa rorun si. Wiwa re nfun ni ni Alafia, oju rere, aanu ati imuse. O npe wa ki a wa sodo re ki a si ri isinmi ninu gbogbo ilakaka wa. Boya isoro naa kere tabi o tobi, ti a ba jeki O dari wa, ao ni sonu. Itosona re ma nso ona gbagungbagun di didan. O si ma nso ogun ainireti di isegun.
BIBELI KIKA: John 14:1-6
ADURA: Jesu, shi oju inu mi lati ri itosona re nipase oro re loni. Amin