JESUS, THE SWEETENER OF LIFE

Silhouette of human hand with open palm praying to god at sunset background

THE SEED

“And Jabez called on the God of Israel, saying,…” 1 Chronicles 4:10(KJV)

Dear brethren, probably you have been burdened and battered with different kinds of difficulties and storms. Alas! I am introducing you to the great Deliverer of all time, the One that needs no introduction, His credits are too long to list, He hails out of the manger in Bethlehem in Jerusalem, He has done the impossible time after time, He walks on water, He turned water to wine, He brought Lazarus who was dead for four days back to life, He Fed 5,000 hungry souls with just two fishes and five loaves of bread. He is the Everlasting Father, the Ruler of the Universe, the King of all kings, the Prince of Peace, the Bright and the Morning Star, Our Saviour, the only Son of the Most High God. His Name is J E S U S. Whatever you have done wrong in your life, repent about it, then tell everything to Jesus. He is with you where you are, He can hear your heart, He will forgive you all your sins, make you His very own, and grant you all those your beautiful heart desires, the joy or happiness of your life you think is lost will be brought back and you will continue to flourish in Christ. Mephibosheth (Son of Jonathan), a Prince, thought he was being forgotten forever, but God remembered him through King David, who brought him back to the palace to eat with the king and gave everything that belonged to King Saul, the predecessor of David and his grandfather.

BIBLE READINGS: 2 Samuel. 9: 1 – 9

PRAYER: Oh Lord I pray, remember me for good in this world and sweeten my life with the Heavenly Home, in Jesus’ Name. Amen

 

 

 

JÉSÙ ẸNITI NSỌ AYÉ DI DÍDÙN

IRUGBIN NAA

“Jábésì sí ke pé Ọlọ́run Israeli, …” 1 Kronika 4:10.

 

Ẹ̀yìn  ará mi olùfẹ́ bóyá o ti wa ninu àjàgà kan ati iporuru pẹlu oniruuru awọn iṣoro ati iji. Ni bayi ngo máa fi  Olugbala nla ti o wa fún gbogbo igba han fún yin, ẹniti ko nilo àfihàn, iṣe rẹ̀, ìyìn rẹ, ati ìṣẹ́un ìfẹ́ rẹ̀,  pọ́ pupọ ju ohùn ti a le ṣé ìròyìn rẹ̀. Ẹnití a bi ni ibùjẹ ẹran ni Betlehemu ni Jerusalemu. O ti ṣe ọpọlọpọ iṣe ko ṣee ṣe ni àìmọye ìgbà. O rìn lori omi, o yi omi pada si ọti-waini, O mu Lasaru ti o ti ku fun ọjọ mẹrin pada wa si aye. O bọ ẹgbẹ̀rún márùn-ún eniyan ti ebi npa, pẹlu ẹja wẹ́wẹ́ meji nikan ati ìṣù àkàrà marun. Ó jẹ baba aiyeraiye, alakoso gbogbo àgbáyé, Ọba awọn ọba, Ọba Alade Alafia, awọn irawọ  Owurọ. Olugbala wa,  ọmọ kanṣoṣo ti Ọlọ́run ọga ogo jùlọ, orukọ rẹ ni JÉSÙ. Ohunkohun ti o ti ṣe aṣiṣe rẹ̀ ninu igbesi aye  rẹ gbiyanju lati ni ẹ̀mí  ẹdùn nipa rẹ, lẹhinna sọ ohun gbogbo fun Jesu; O wa pẹlu rẹ  nibiti o wa, O le gbọ ẹdùn ọkàn rẹ, yio dari  gbogbo ẹṣẹ rẹ ji ọ.Yio sọ ọ di tirẹ gan-an gan yio fun ọ ni gbogbo awọn ohun ti o dára tí ọkan rẹ nfẹ;  ayọ tabi ìdùnnú fún ayé rẹ ti o ro pe o ti padanu, yio pada wa ìwọ yio tẹsiwaju lati dagba ninu Kristi. Mefibóṣẹ́tì ọmọ Jonatani ọmọ alade ro pe a gbagbe òun lailai, ṣugbọn Ọlọrun ranti rẹ nipasẹ ọba Dafidi ti o mu u pada si aafin lati jẹun pẹlu ọba;  a si fun ni ohun gbogbo ti o jẹ́ ti ọba Saulu ti o ti ṣáájú Dafidi ati baba nla rẹ̀.

 

BIBELI KIKA: 2 Samueli 9:1-9

ADURA: Oluwa mo gbadura ki o ranti mi fun rere ni aye yi ki o si mu aye mi dun pẹ̀lú ile ọ̀run l‏órúkọ Jesu.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *