THE SEED
“I am the vine, you are the branches. He who abides in Me, and I in him, bears much fruit; for without Me you can do nothing.” John 15:5 NKJV
Dearly beloved, There are two parts to our existence: the part that is visible to the world and the hidden part that no one can see. It’s the visible part that manifests the fruit of the Spirit which is love, joy, peace, patience, kindness, goodness, gentleness, faithfulness, and self-control. But like the roots of an oak tree below the surface and hidden taps of life from the underground water, so does our soul, the hidden part of our being taps life from the Spirit, communing with God’s Spirit through time in the Word, moments in prayer, and occasions of worship. No one can see these things. They are done in a secret place, below the surface. But they are key to fruitfulness. It’s from there that you can receive spiritual nourishment by which you can be fruitful. We take our strength and nourishment to bear fruits for our Lord Jesus and that is the reason He said in the opening Scripture that ‘without me, you can do nothing. Being in a good relationship with the Lord Jesus is our key to both divine and earthly fruitfulness.
PRAYER
Lord Jesus, you are the key to my fruitfulness, help me to be close to you all the days of my life. Amen
BIBLE READINGS: John 15:1-5
KOKORO FUN SISO ESO
IRUGBIN NAA
“Èmi ni àjàrà, eyin ni eka. Ẹniti o ba ngbe inu mi, ati emi ninu rẹ, o nso eso pupọ; nitori laisi mi iwọ ko le ṣe ohunkohun.” Johannu 15:5
Eyin ololufe, Apa meji lo wa ninu aye wa: apa ti o han si aye ati apa ti o farasin ti enikeni ko le ri. Apa eleyi ti ko farasin lo maa n se afihan ESO ti Ẹmi ti o je ifẹ, ayọ, alaafia, sũru, inurere, rere, iwa pẹlẹ, otitọ, ati ikora-ẹni-nijaanu. Ṣugbọn gẹgẹ bi awọn gbòngbo igi oaku ti o wa ni isalẹ ilẹ ati awọn omi iye ti o farapamọ ni abẹ ile, bẹ naa ni ẹmi wa eyi ti o farapamo bi omi iye nínú emi, ti n ba emiolorun soro nipa akoko nínú oro,nínú adura àti ninu iisin.Ko si eniti o le ri nkan wọnyi. A se won ni bi ìkọko, labẹ ile. Ṣugbọn wọn jẹ kokoro fun eso siso. Lati ibẹ ni o le gba ounjẹ ti ẹmi nipasẹ eyiti o le Fi so eso. A ń gba okun àti oúnjẹ wa láti so èso fún Jésù Olúwa wa ìdí nìyẹn tí Ó fi sọ nínú Ìwé Mímo tí ó be re pé ‘Láìsí mi, ẹ kò lè ṣe nǹkan kan. Wíwá ni ibasepo rere pelu Jesu Oluwa jẹ kọkọrọ wa fun siso eso ti orun àti ti aye.
ADURA
Jesu Oluwa, iwo ni kokoro si siso eso mi, ran mi lowo lati sunmo o ni gbogbo ojo aye mi. Amin
BIBELI KIKA: Jòhánù 15:1-5