Keys To Effectual Prayers

THE SEED
“And I say unto you, Ask, and it shall be given you; seek, and ye shall find; knock, and it shall be opened unto you.” Luke 11:9

For some of us, it is hard to pray with consistency during the week. For others, we may struggle with what to pray for, while some of us don’t pray much to God at all. No matter our circumstances, we have the privilege of praying to our Father who is in heaven, and so we should pray! In the scripture above, Jesus says if we apply the principles of asking, seeking, and
knocking, we will always have answers to our prayers. If you asked and it seems you have not received, apply the second principle by seeking, which means continuous searching. If it seems
you have not found what you are seeking, then apply the last principle by knocking. Dearly beloved, we only knock at a closed door – as you keep knocking, it will surely open. Determination and effectual prayer are needed; therefore, let us not give up too easily.

PRAYER
O Lord grant me the grace to pray fervently in Jesus name Amen

BIBLE READINGS: Luke 11: 1-13

AWỌN KỌKỌRỌ FUN ÁDÙRÁ TO DÁJÚ
IRÚGBÌN NÁÀ.
“Mo si wi fun nyin, Bère a o si fifun nyin, ẹ wá kiri, ẹnyin o si ri; kànkun, a o si ṣí i fun nyin.” Luku 11:9

Bẹ̃ni diẹ ninu wa ni o nira fún lati gbadura deede laarin ọsẹ. Fun awọn miiran, a le tiraka pẹlu ohun ti a ngbadura fun, nigbati diẹ ninu wa ko gbàdúrà pupọ si Ọlọrun rara. Laibikita iru
ipò tí a wa, a ni anfaani lati gbadura si baba wa ti o Ó wà ní ọ̀run, nítorí náà a gbọ́ dọ̀ máa gbàdúrà! Nínú ìwé mímọ́ tó wà lókè, Jésù sọ pé bí a bá ló àwọn ìlànà bíbéèrè, wíwá àti kíkànkùn,
a ó máa rí ìdáhùn àdúrà wa nígbà gbogbo. Ti o bá béèrè tí o rí pe o ko rí ìdáhùn, o le ló Ìlànà kejì nípa wíwá, èyí tí ó túmọ̀ sí wíwá kiri ní gbogbo ìgbà. Bí ó bá dà bí ẹni pé o kò rí ohun tí o ń wá gba, fi ìlànà tí ó kẹ́yìn sí lilò nípa kíkànkùn. Olùfẹ́ ọwọn ilẹkùn tí o ba tí ni a máa nkan- bí o tí nkan ilẹkùn, o di dandan kí o ṣi. Ipinu ati adura ti o munadoko ni a nilo, nitorina, maṣe jẹ ki o su ọ.

ADURA
Oluwa fun mi ni oore-ofe lati gbadura kikan ni oruko Jesu Amin.

BIBELI KIKA: Luku 11: 1-13

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *