LAUNCH OUT INTO THE DEEP

THE SEED

“Now when he had left speaking, he said unto Simon, Launch out into the deep, and let down your nets for a draught.” – Luke 5:4 (KJV)

Peter and his team had toiled all night and caught nothing. But at Jesus’ word, everything changed. Divine instruction can do in one moment what human effort cannot do in years.

When life’s struggles leave you empty, what you need is not more strategies but a word from the Master. Build intimacy with Him through prayer and His Word, and be sensitive to His instructions. Trust and obey — and watch Him bring a net-breaking miracle into your life.

BIBLE READINGS:  Luke 5:1–11 (KJV)

PRAYER: Lord, give me clear divine instruction for my life today, and help me to trust and obey Your Word. Amen.

JADE LO SINU IBU

IRUGBIN NAA

Bi o si ti dakẹ ọ̀rọ isọ, o wi fun Simoni pe, Tì si ibu, ki o si jù àwọn nyin si isalẹ fun akopọ̀. Luku 5:4

Peteru ati awon eniyan re ti sise ni gbogbo our ti won ko si ri ounkoun mu. Sugbon nipa oro Jesu, oungbogbo yipada. Idari lati orun wa le seun ni iseju kan ti agbara eniyan ko le se ni opolopo odun. Nigba ti ilakaka aye ba so eniyan di ofifo, kiise eto miran lo nilo, sugbon kiki oro lati odo Oluwa. Ni ibasepo timotimo pelu re nipa adura ati oro re. si okan re paya si idari re. gbekele ki o si gboran, ki o si wo bi yio se mu iyanu ti nge awon wonu aye re.

BIBELI KIKA: Luku 5:1-11

ADURA: Oluwa fun mi ni idari ti o mole kedere lati orun wa fun aye mi loni, kio si ranmilowo lati gbekele, kin si gboran si oro re. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *