LEAVING A GODLY LEGACY

THE SEED

“Thus saith the Lord God; This shall be the border, whereby ye shall inherit the land according to the twelve tribes of Israel: Joseph shall have two portions.” – Ezekiel 47:13 (KJV)

Joseph’s good deeds in Egypt were remembered long after his death. God instructed that Joseph’s tribe receive double portions in the land. Good works done in obedience to God are never forgotten.

When we live righteously and serve faithfully, the blessings extend beyond us to future generations. Strive to leave a godly legacy that brings honour to God and blessings to your descendants. Psalm 112 reminds us that the generation of the righteous will be blessed.

BIBLE READINGS:  Psalm 112:1–3 (KJV)

PRAYER: Lord, help me to live a life that will bring Your goodness upon me and generations to come. Amen.

FIFI OGUN RERE TI OLORUN LE ILE.

IRUGBIN NAA

Bayi li Oluwa Ọlọrun wi; eyi ni yio jẹ ãlà, ti ẹnyin o fi jogún ilẹ na fun ara nyin fun ẹ̀ya mejila Israeli: Josefu yio ni ipin meji.Ezekiel 47:13

Ise rere ti Josefu se ni ilu egipiti je oun ti won ranti fun igba pipe lehin ti o ti ku. Olorun dari won wipe ki eya Josefu gba ilopo meji ni ile naa. Ise rere ti a se ninu igboran si Olorun o kii di igbagbe. Ti a ba ngbe igbe aye ododo, ti a si nsin lotito, Ibukun naa ma ntayo koja wa lo si iran ti o mbo lehin. Gbiyanju lati fi ogun rere sile , eyi ti o buyi kun Olorun ti o si mu Ibukun ba iwo ati irandiran re. orin Dafidi 112 ran wa leti wipe Ibukun ni fun iran awon olododo.

BIBELI KIKA: Orin Dafidi 112:1-3

ADURA: Oluwa, ranmilowo lati gbe igbe aye ti yio mu ire re wa si ori mi ati iran ti nbo. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *