LORD YOUR WORD IS MY DELIGHT

THE SEED

”Your words were found, and I ate them, and your words became to me a joy and the delight of my heart, for I am called by your name, O Lord, God of hosts.“ Jeremiah 15:16

Our identity as children of God is linked to the word of God. It is our major sustenance. The major way to identify ourselves as God’s is by studying, meditating, doing and teaching the word of God; our life becomes the beacon of God’s word. Prophet Jeremiah said, “Thy words were found, and I did eat them;” As the year runs out, in our reflection, let us ask ourselves how much of the word of God we have consumed and kept in mind. When we eat food, it goes into our body in the process of digestion and the nutrients are absorbed into the parts of the body that need them; so is the word of God we study, meditate upon and live out. A Christian without the word has no connection with God and runs the risk of being overpowered by temptation and deceit from the enemy. The word of God is the activator of our joy and peace. As the body needs physical food to maintain stability and nourishment, so do our soul and spirit need the word of God to grow and flourish. Let us strive to feed spiritually well to keep our souls delighted and maintain proper spiritual growth. 

BIBLE READINGS:  Psalm 119:23-24.

PRAYER: Heavenly Father, help me to thirst for your word to make it a delight to my soul, in Jesus’ name. Amen 

 

Ọ̀RỌ̀ RẸ̀ NI INU DIDUN MÍ

IRUGBIN NAA

“Nigbati a rí ọ̀rọ̀ rẹ, emi sí jẹ wọ́n,  ọ̀rọ̀ Rẹ̀ sí jẹ inú dídún mì, nítorí orúkọ Rẹ̀ ní a fí ńpè mì, ìwọ Olúwa, Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún” Jeremáyà 15:16

Idanimọ wa, bi awọn ọmọ Ọlọrun ni isopọ wa pẹlu ọrọ Ọlọrun.  O jẹ ohun elo pataki to gbé wa ro.  Ọ̀nà pàtàkì láti dá ara wa mọ̀ bí ọmọ Ọlọ́run ni, nípa kíkẹ́kọ̀ọ́, ṣíṣe àṣàrò, ṣíṣe àti kíkọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run;  aye wa yio di ìtọ́nṣàn imọlẹ ti ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.  Wòlíì Jeremáyà sọ pé: “A rí ọ̀rọ̀ rẹ, mo sì jẹ wọ́n”.  Bí ọdún ṣe ń lọ sí òpin, nínú ìrònú wa, ẹ jẹ́ ká bi ara wa léèrè mélòó nínú ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tí a ti jẹ, tí a sì fi sínú ọkàn wa. Nigba ti a ba jẹ ounjẹ, yio lọ sinu ara wa, ni ilana ti to nkan lẹsẹsẹ ati awọn eroja ti a gba sinu awọn ẹya ara, bi ara ti nilo wọn;  bẹ́ẹ̀ náà ni ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tí a ń kẹ́kọ̀ọ́, ti máa ńṣe àṣàrò lé lórí, tí a sì ń gbé jáde.  Onigbagbọ laisi ọrọ, ko ni idapọ pẹlu Ọlọrun, ati pe o wa ninu ewu idanwo ati ẹtan lati ọdọ ọta.  Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ló ń mú ayọ̀ àti àlàáfíà wa, ṣiṣẹ́.  Bi ara ṣe nilo ounjẹ fún  iduroṣinṣin ati lati ṣetọju ara, bẹẹ ni ẹmi  wa nilo ọrọ Ọlọrun lati dagba ati gbilẹ.  Ẹ jẹ́kí a gbiyanju lati fún ẹ̀mí ní oúnjẹ ki o le fun ọkàn wà  ni ìdùnnú ati ìdàgbàsókè ẹ̀mí tí o peye.

BIBELI KIKA: Psalmu 119:23-24

ADURA: Baba ọ̀run ran mi lọ́wọ́ lati pon gbẹ fun ọ̀rọ̀ Rẹ̀, ki o lé jẹ́ inú dídún si ọkàn mi lórúko Jesu Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *