LOVING GOD

THE SEED
“Love the Lord your God…” Mark 12:30

Jesus taught that loving God is the greatest commandment, and that the second greatest command is to love our neighbor as ourself. Then one of the greatest questions must be “What is love?” In 1 Corinthians 13 we find a beautiful answer. Paul’s words in that chapter guide our understanding of love on the basis of God’s love for us. And we can apply that to our love for God as well as for our neighbour. Are we ever impatient with God? Are we unkind to God? Do we envy God in any way? Are we ever boastful, taking credit for what God enables us to do? Are we rude to God? Are we self-seeking, forgetting to love God first? Are we easily angered by God? Do we keep a mental record of the ways we think God has wronged us? Do we delight secretly in evil that breaks God’s heart? Or do we trust, hope, and persevere in doing what is right, to honour God? (See 1 Corinthians 13:4-7.) How much we have to grow in love, remember, though, that God first loved us. He is infinitely patient and eternally kind. And God’s love “never fails” (1 Corinthians 13:8).

BIBLE READING: MARK 12:28-34

PRAYER: Lord, we confess that we often fall short of showing your love to you as well as others. Forgive us, and help us to love the way you do. Amen.

ỌLỌRUN ONIFẸ BIBELI KIKA

IRUGBIN NAA

“Ki iwọ kì o sí fi gbogbo àyà rẹ, àti gbogbo ọkàn rẹ, ati gbogbo iye rẹ, àti gbogbo agbara rẹ, fẹ Oluwa Ọlọrun rẹ: èyí ni òfin èkíní.” Maku 12:30

Jesu kọ wa pe, ifẹran Ọlọrun ni ofin ti o tobi julọ, ati pe aṣẹ keji ti o tobi julọ ni lati nifẹ awọn aladugbo wa bi ara wa. Nigbana ni ọkan ninu ibeere ti o tobi julọ gbọdọ jẹ “Kini ifẹ” Nínú 1 Korinti 13. a ri idahun ti o dára jùlọ.  Ọ̀rọ̀ Pọ́ọ̀lù nínú orí Bíbélì kíkà akọkọ ń darí òye wa nípa ìfẹ́ tí o jẹ ìpìlẹ̀ ìfẹ́ tí Ọlọ́run fún wa.  A sì lè fi ìfẹ́ tí a ní fún Ọlọ́run àti fún àwọn aládùúgbò wa. Njẹ o ni suuru pẹlu Ọlọrun bi?  Ǹjẹ́ o ní ọkàn tí kò mọ oore níwájú Ọlọ́run bí?  Njẹ o máa ń ṣe ìlara nipa gbigba orí ìyìn fún ohun ti Ọlọrun ran ọ lọwọ láti ṣe?  Njẹ a nwa tí ara wa nikan, ti a sí gbàgbé ìfẹ Ọlọrun akọkọ? Njẹ Ọlọrun ha ntètè nbi wa ninu? Njẹ o máà nfi nkan pamọ́ si ọkan ni oríṣi ọna ti a gbà pé Ọlọrun ṣẹ wá? Njẹ a ní inudidùn sí ohùn ikọkọ búburú tí a nṣe ti o nbi Ọlọrun nínú bí? Njẹ a ni igbẹkẹle, ìrètí, tabi itara ni ṣiṣe ohun tí o tọ tí o sí bọla  fún Ọlọrun? (wo 1 Kọ́ríńtì 13:4-7). Kíni a ni, lati dagba ninu ifẹ! Rántí pé nípa èyí ni Ọlọ́run kọ́kọ́ nífẹ̀ẹ́ wa.  O ni suuru ailopin ati inu réré ti ayérayé.  Ìfẹ́ Ọlọ́run  “kì í kùnà láé.” (1 Kọ́ríńtì 13:8)

BIBELI KIKA: Máàkù 12:28-34

ADURA: Oluwa a jẹwọ wipe a maa nkúna láti fi ìfẹ Rẹ han si Ọ pẹlú àwọn ẹlòmíràn.  Dariji wa, ki o si ran wa lọwọ lati nifẹ, lọna ti Ò gbà fẹ wa.  Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *