NO CONDITION IS PERMANENT

THE SEED

“Who art thou, O great mountain? before Zerubbabel thou shalt become a plain.” – Zechariah 4:7a (KJV)

No mountain is too great for God to level. Naaman was a mighty man with a hidden affliction, but God turned his story around. Being a child of God doesn’t exempt us from challenges, but it guarantees victory in the end. Life’s problems are temporary. They will pass if we hold on to God. Just as Naaman’s leprosy was cleansed and his shame turned to testimony, your mountain too shall become a plain. Trust the One who moves mountains with ease.

BIBLE READINGS:  2 Kings 5:1–14 (KJV)

PRAYER: Oh Lord, give me victory over every mountain that stands as a challenge in my life. Let every obstacle melt before Your power, in Jesus’ name. Amen.

KO SI IPO TI YIO WA TITI

IRUGBIN NAA

Tani iwọ, Iwọ oke nla? iwọ o di pẹ̀tẹlẹ niwaju Serubbabeli: on o si fi ariwo mu okuta tenté ori rẹ̀ wá, yio ma kigbe wipe, Ore-ọfẹ, ore-ọfẹ si i. Zechariah 4:7a

Ko si oke ti o ga ju fun Olorun lati mu wa sile. Namani je alagbara okurin ti o ni ailera ti o pamo, sugbon Olorun yi itan re pada. Toriwipe a je omo Olorun ko ni wipe ao ni ri ipenija, sugbon o fun wa ni idaniloju isegun ni ikehin. Fun igba die ni awon isoro aye, won yio koja lo ti a ba di Olorun mu. Gege bi Namani se ri imularada ti egan re pada di eri rere, oke tire naa ma di petele. Gbekele eni ti o nfi irorun si oke ni idi.

BIBELI KIKA: 2 Oba 5:1-14

ADURA: Oluwa, fun mi ni isegun lori gbogbo oke ti o duro gegebi ipenija ninu aye mi, jeki gbogbo idena ki o tuka niwaju agbara re ni oruko jesu. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *