OUR HOMES

THE SEED
“And if I go and prepare a place for you, I will come again, and receive you unto myself; that where I am, there ye may be also.” John 14:3(KJV).

Our home is with Jesus Christ and the place he has prepared for us is “Heaven”. This home is better than anything we could imagine on Earth. Better than any luxurious mansions or beachfront; we will be in God’s presence till eternity. This is the ultimate home like no other, where we get to be with our Lord; Earth is a journey. Jesus said,” In my father’s house are many mansions” As Christians, making heaven should be our primary goal. It is good to have wealth, to build houses, to have cars, etc, but we must remember our Eternal home. And the only way to do this is to maintain a proper relationship with Jesus Christ. Your denomination and title do not matter; what matters is your primary goal. Allow nothing to take you to hell including False Teachers and Churches that are not teaching the undiluted word of God. Be watchful at all times, take your Christian life seriously, and follow the example of Jesus Christ. As a child of God, if heaven is not your primary goal you are wasting your time. The question is, Is your name written in the Book of Life? If yes, Congratulations, and if No, there is still room for adjustment.

BIBLE READINGS: John 14: 2 – 4

PRAYER: Lord Jesus, give me the grace to make heaven in Jesus’ Name. Amen.

ILÉ WA

IRUGBIN NAA

“Bi mo bá sí lọ ìpèsè àyè silẹ fún yín, èmi o tún padà wá èmi o si mu yín lọ sọ́dọ̀ èmi tìkárami; pe nibiti èmi gbé wa. Ki ẹ̀yìn lé wa níbẹ̀ pẹ̀lú.” Johannu 14:3

 

Ile wa, wà pẹ̀lú Jesu Kristi ati ibi ti o ti pese sílẹ̀ fun wa ni “Ọrùn” ṣùgbọ́n ile yi dára jù ohunkóhun tí a lé rò lọ lórí ilẹ aye; o dára ju àwọn ilé ńlá tí ó ni ẹwà tàbí ìgbádùn etí òkun. Ao wa niwaju Ọlọ́run títì ayérayé.  Ilé ikẹhin tí kò lafiwe, ti a o de si ibẹ pẹ̀lú Olúwa. Aye jẹ irin ajo. Jesu sọ pe “Ni ile baba mi ọpọlọpọ awọn ibùgbé ni o wa nibẹ” gẹ́gẹ́ bi Kristiani lati de ọrun yẹ ki o jẹ erongba wa akọkọ. O dára lati ni ọrọ̀, lati kọ àwọn ile, lati ni awọn ọkọ ayọkẹlẹ ati bẹbẹ lọ; ṣugbọn  a gbọdọ ranti ile ayeraye wa, ati pe ọna kan ṣoṣo lati ṣe eyi ni lati ṣe tọju ibaṣepọ to dara pẹlu Jesu Kristi.

Orúkọ ile  ìjọsìn rẹ ati akọle òye rẹ ko jẹ pataki; ohun ti o ṣe pataki ni erongba rẹ akọkọ. Ma ṣé jẹ ki ohunkóhun mú ọ lọ si ọ̀run àpáàdì pẹlu awọn olukọ eke ati awọn ilé ijọsin ti kii kọ ni, ni ẹ̀kọ́ ti ó yè kooro, ṣugbọn awọn ẹ̀kọ́ ti ó ni àmúlu mala ọ̀rọ̀. Máà ṣọ́ra nígbà gbogbo, mú ìgbé ayé Kristẹni rẹ gìrì kí o sì tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jésù Krístì. Gẹgẹ ́ bí ọmọ Ọlọ́run, tí ọ̀run kì í bá ṣe èrò ti o jẹ́ ọ̀ lọ́kàn  o ń fi àkókò rẹ ṣòfò. Ìbéèrè náà ni pé, njẹ a kọ orúkọ rẹ sínú Ìwé iye? ti o ba jẹ bẹẹni o ku oriire, ti ko ba si ri bẹ́ẹ̀ aye wa fun awọn atunṣe.

 

BIBELI KIKA: Johannu 14: 2-4

ADURA: Jesu Oluwa fun mi ni oore-ọfẹ lati de ọrun, ni orukọ Jesu Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *