THE SEED
“A double minded man is unstable in all his ways.” – James 1:8 (KJV)
Doubt is not just the opposite of faith — it is rooted in fear. When doubt is allowed to grow, it leads to fear, which then produces unbelief, and unbelief paralyzes faith. A paralyzed faith cannot receive from God. A doubter is like a wave of the sea, easily tossed around and unable to stand firm. God can do anything — He holds the firmament without pillars — but doubt blocks us from receiving from Him. When we doubt God, we are indirectly saying, “I don’t trust You.” Doubt is one of the enemy’s most subtle weapons to weaken a believer’s confidence in God. Without faith, it is impossible to please Him. Guard your heart, feed your faith, and resist doubt immediately.
BIBLE READINGS: Mark 11:20–24 (KJV)
PRAYER: Lord Jesus, help me to uproot every seed of doubt in me. Strengthen my faith to move mountains, in Jesus’ name. Amen.
BIBORI IYEMEJI
IRUGBIN NAA
Enia oniyemeji jẹ alaiduro ni ọ̀na rẹ̀ gbogbo. James 1:8
Iyemeji je idakeji igbagbo, sugbon ju bee lo, o fi ese mule ninu eru. Ti a ba gba iyemeji laaye lati dagba, o ma jasi eru, eyi ti o ma mu aigbagbo wa, ti o si nso igbagbo di aro. Igbagbo to ya aro ko le ri oun gba lodo Olorun. Eni ti o se iyemeji, o dabi igbi okun, ton lo si iwa sehin ti ko si le duro sinsin. Olorun le se ounkoun, o di ofurufu mu lai fi ounkoun dii mu sugbon iyemeji a maa di wa lona lati gba lowo re. ti a ba se iyemeji si olorun, oun ti a nso ni wipe “mi o gbeke mi le o”. iyemeji je okan lara awon irin ise ota lati mu igboya won ninu olorun kere. Laisi igbagbo, ko seese lati wuu . toju okan re, jeki igbabo re dagba kio si koju ija si iyemeji lesekese
BIBELI KIKA: Mark 11:20-24
ADURA: Jesu Oluwa, ranmilowo lati tu gbogbo eso iyemeji ninu mi kuro. Ran igbagbo mi lowo lati si oke nidi loruko Jesu , Amin.