Possibilities With God

THE SEED
“And he said, The things which are impossible with men are possible with God.” Luke 18:27

There is nothing impossible to him that believes. Whatever you believe, that is what you see and that is what you become. Faith is your major access if God must do the impossible and it is not optional as a Christian, it is a must. It doesn’t matter what you’re believing God for—you don’t have to consider the circumstances that surround your particular situation. If you start thinking about all the natural conditions or what So-and-so said, you will become weak in faith. That challenge that looks as though it is the end of existence for you, that little cash in your purse which is all you have and you do not know how the next meal will come, oh! that treasury that looks empty with no hope of filling it up. All things around you might be seeming impossible…But wait a minute, there is hope and don’t give up yet

BIBLE READING: Luke 18

PRAYER: Lord, I believe that there is possibility in that which seems impossible. It is in THE GOD OF ALL POSSIBILITIES

OUN GBOGBO NI SISE PELU ỌLORUN

IRUGBIN NAA
“O si wipe, Ohun ti ko se e se fun eniyan, pelú Ọlorun oun Gbogbo ni sise.” Lúùkù 18:27

Ko si ohun ti ko ṣee ṣe fun ẹniti o gbagbọ. Ohunkohun ti o gbagbọ, iyẹn ni ohun ti o rii ati pe ohun si ni Iwo yio je. Igbagbọ ni irinse re ti Ọlọrun yio lo lati se oun ti ko ṣee ṣe ati pe kii ṣe oun aigbudo Mani bi Onigbagbọ, o jẹ dandan. Ohun ti o ngba Ọlọrun gbọ fun ko se Pataki, iwọ ko gbudọ jeki o yika nipa Lori re. Ti o ba bẹrẹ si ronu nipa gbogbo awọn idojuko re tabi ohun ti awon eniyan so, iwọ yoo di alailagbara ninu igbagbọ. Ipenija yẹn ti o dabi ẹnipe o jẹ opin aye fun ọ, owo kekere yẹn ninu apamọwọ rẹ eyiti o jẹ gbogbo ohun ti o ni ati pe o ko mọ bii ounjẹ ola yio se de,tabi iṣura re ti o ti tan ti o si dabi eniti ko ni ireti mo, gbogbo ohun ti o wa ni ayika rẹ le dabi ẹnipe ko ṣeeṣe, Ṣugbọn duro fun iṣẹju kan, ireti wa ati maṣe so ireti nu.

BIBELI KIKA: Lúùkù 18

ADURA: Oluwa, mo gbagbo wipe aseyori wa ninu eyi ti o dabi ẹnipe ko ṣee ṣe. O wa ninu ỌLỌRUN TI O LE SE OHUN GBOGBO.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *