THE SEED
“Ye ask, and receive not, because ye ask amiss, that ye may consume it upon your lusts:” James 4:3
The key to praying rightly is to pray with the right steps that get you connected to God’s heart for a vibrant prayer life. Jesus Christ did not want the disciples of his day and those of today to pray amiss so he gave a format for prayer. (Matt: 6:9.) First of all, you need to acknowledge God as your Father; meaning you need to have a personal relationship with him. Secondly, worship and praise him, and welcome his presence. Thirdly, ask his will to be done in your life as it is in heaven. Fourthly, ask for your pressing need especially your daily provision. Fifthly, forgive all who have wronged you and ask God to also forgive you for your sins. Sixthly, pray for his power of deliverance from evil and temptation. When we are about to pray, we should have all these prayer steps at the back of our mind, especially worship/praise, and thanksgiving before our request; as we do these in faith and receive in faith every prayer we make will be made in joy.
BIBLE READING: Matt: 6:9
PRAYER: Lord, help me to pray without ceasing
MASE SI ADÚRÀ GBA
IRUGBIN NAA
“Enyin beere, e ko si ri gba, nitoriti enyin si beere,ki eyin ki o le lo o fun ifekufe okan yin” Jakobu 4:3
Kokoro Lati gbadura lonà ti o to ni lati gbadúrà pelu ìgbése ti o to eyi ti yo so o po pelú Okan Ọlorun fun igbe aye Adura ti o munadoko. Jesu Kristi ko fẹ ki awọn ọmọ-ẹhin rẹ igbaani ati awọn ti ode oni ki won si Adura gba, nitori naa o ko won Lati maa gbadura. ( Mát: 6:9 ) Lákoko, o gbodo gbà pé Ọlorun ni Baba rẹ; eyi ti o túmo si pe o nilo lati ni ìbáṣepo pẹlu rẹ. Èkejì, sìn ín, kí o sì yìn ín, kí o sì faye gba ifarahan re. Ẹkẹta, beere fun ifẹ rẹ lati di mimuse ninu aye rẹ bi won ti n se ni ọrun. Ekẹrin, beere fun oun ti o nilo paapaa ipese ojoojumọ rẹ. Ikarun, dariji gbogbo awọn ti o ti ṣe ọ ki o si beere lọwọ Ọlọrun lati tun dari ẹṣẹ rẹ jì ọ. Ni ẹkẹfa, gbadura fun agbara igbala rẹ kuro ninu ibi ati idanwo. Nigba ti a ba fẹ gbadura, o yẹ ki a ni gbogbo awọn igbesẹ adura wọnyi ni ẹhin ọkan wa, paapaa ijosin atí iyin, ati idupẹ ṣaaju ibere wa; bí a ti ń ṣe àwọn nǹkan wonyí nínú ìgbàgbo tí a sì ń fi Okan ìgbàgbo gba,gbogbo àdúrà tí a bá gbà yóò yori sayo..
BIBELI KIKA: Mátiu 6:9
ADURA: Oluwa, ranmilowo lati gbadura laisimi.