THE SEED
Praying always with all prayer and supplication in the Spirit, being watchful to this end with all perseverance and supplication for all the saints. Ephesians 6:18
Prayers led by the Holy Spirit are efficient and powerful. Jesus encouraged the disciples, by telling them that after His departure from this earth, His Father would send them “another” Helper, meaning “one of the same kind,” someone like Him. The Lord referred to the Holy Spirit who is one of the three persons of God’s trinity. Jesus had to deal with the limits of time and space while on earth, living in a human body, that could only be in one place at a time. The Holy Spirit is God and omnipresent, there is no place that He is not present. Through Him, God the Father and the Son live in our hearts. Jesus said:“But the Helper, the Holy Spirit, whom the Father will send in My name, He will teach you all things, and bring to your remembrance all things that I said to you” (John 14:26). The Holy Spirit knows all things and everything we need. If we ask Him to help us pray and teach us what we need to know, He will do it. If we pray under the anointing of the Holy Spirit, to Father God, in the Name of Jesus, we know that we pray according to God’s will and we will receive what we are asking for. If we are truly led by the Holy Spirit, we will pray for what the Lord wants to give us, because He knows better than we do, what is best for us and others. In the “Holy Spirit Articles” section, you may find more information about who He is, what He does, His fruit, His gifts and the baptism with the Holy Spirit.
BIBLE READING: ACT 1 & 2
PRAYER: Please help me to stay alert, to hear Your advice, warnings and urge to intercede in prayer for all God’s people that You lay on my heart. Thank You Lord for the power that You gave us through prayer and please help me to use it right in the Name of Jesus. Amen.
ÀDÚRÀ NÍNÚ Ẹ̀MÍ
IRUGBIN NAA
Ẹ máa gbàdúrà nígbà gbogbo, pẹ̀lú gbogbo àdúrà àti ẹ̀bẹ̀ nínú Ẹ̀mí, kí ẹ máa ṣọ́rà síi ninu ìdúróṣinṣin gbogbo àti ẹ̀bẹ̀ fún gbogbo àwọn ènìyàn mímọ́. Éfésù 6:18
Àdúrà tí a fí Ẹ̀mí Mímọ́ ń darí jẹ́ eyi ti o muna ti ó sì lágbára. Jésù gba àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ níyànjú, nípa sísọ fún wọn pé l’ẹ́yìn tí òun bá kúrò ní ilé ayé, Bàbá òun yóò rán “Olùrànlọ́wọ́ mìíràn” sí wọn, tó túmọ̀ sí ẹnì kan náà bíi tìrẹ. Oluwa tọka si Ẹmi Mimọ ti o jẹ ọkan ninu mẹta ninu Ọlọrun Mẹtalọkan. Jesu ni lati koju iwọn akoko ati aaye nigba ti o wa lori ilẹ-aye, nigbati o ngbe inu ara bi eniyan; èyí fi yé wa pé Jésù le wa ni ibi kan ni akoko kan. Ẹ̀mí mímọ́ ni Ọlọ́run, ẹniti o nwa ní ibi gbogbo nigbagbogbo: kò sí ibi tí kò síi. Nípasẹ̀ rẹ̀, Ọlọ́run Baba àti Ọmọ ń gbé nínú ọkàn wa. Jésù sọ pé: “Ṣùgbọ́n Olùrànlọ́wọ́, ti nṣe Ẹ̀mí mímọ́, ẹni tí Baba yóò rán ní orúkọ mi, yíó kọ́ yín ní ohun gbogbo, yió sì mú ohun gbogbo wá sí ìrántí yín, awọn ohun tí mo ti wi fun nyin” (Johannu 14:26). Ẹmí Mimọ mọ ohun gbogbo ati ohun gbogbo ti a nilo. Ti a ba beere lọwọ Rẹ lati ran wa lọwọ lati gbadura ki o si kọ wa ní ohun ti a nilo lati mọ, Oun yíò ṣe. Ti a ba gbadura labẹ ifo roro yan Ẹ̀mi Mímọ, si Ọlọrun Bàbá, ni Oruko Jesu, a mo pe a gbadura gẹgẹ bi ifẹ Ọlọrun, a o si gba ohun ti a nbere fun. Tí Ẹ̀mí Mímọ́ bá ń darí wa lóòtọ́, a máa gbàdúrà fún ohun tí Olúwa fẹ́ fún wa, torí pé ó mọ̀ ju wa lọ, ati ohun tó dára jù lọ fún wa àti àwọn míràn. Ninu awọn akọsilẹ nipa “Awọn nkan ti Ẹmi Mimọ”, o le wa awọn alaye diẹ sii nipa ẹniti ẹmi mímọ jẹ, ohun ti O nṣe, eso Rẹ, awọn ẹbun Rẹ ati ibaptisi pẹlu Ẹmi Mimọ.
BIBELI KIKA: Iṣe Awọn Àpọsítélì 1 & 2
ADURA: Jọwọ ran mi lọwọ lati wa ni igbaradi, lati gbọ imọran Rẹ, awọn ikilọ ati igba ni níyàju lati ṣipẹ ninu adura fun gbogbo eniyan Ọlọrun ti o fi le ọkan mi. Adupe lọwọ Oluwa fun agbara ti O fun wa nipa adura ati jọwọ ran mi lọwọ lati lo ní ọnà tí o tọ lórúkọ Jesu.