THE SEED
“But Daniel purposed in his heart that he would not defile himself with the portion of the king’s meat.” – Daniel 1:8 (KJV)
In a world that pressures us to conform, Daniel’s example reminds us of the importance of conviction. Daniel resolved not to defile himself with the king’s food, choosing faithfulness over conformity. Like Daniel, we are called to purpose in our hearts to live in a way that honors God. Our choices today shape our testimony for tomorrow. Though it takes courage to stand apart, God honors those who remain faithful. May we purpose in our hearts to follow God wholeheartedly, even when challenged.
BIBLE READING: Daniel 1:1-8
PRAYER: Lord, help me to purpose in my heart to remain faithful to You. Strengthen my resolve to live according to Your will. Amen.
ERONGBA NÍNÚ ỌKÀN RẸ
IRUGBIN NAA
“Ṣùgbọ́n Dáníẹ́lì pinnu rẹ̀ nínú ọkàn rẹ̀ pé, òun kí yío fí oúnjẹ adidun ọba, àti ọtí wáìnì tí o mú bá ará òun jẹ́: nítorí náa o bẹ olórí àwọn ìwòfà pé, kí òun má ba ba ara òun jẹ.” Dáníẹ́lì 1:8
Nínú ayé tó ń fipá mú wa láti tẹ̀ lé ohun ayé, àpẹẹrẹ Dáníẹ́lì rán wa létí, ìjẹ́pàtàkì ni tí ìdánilójú. Dáníẹ́lì pinnu láti má ṣe fi oúnjẹ ọba sọ ara rẹ̀ di ẹlẹ́gbin, ó yan ìṣòtítọ́ ju ìbáṣèpọ. Bí i Dáníẹ́lì, a pè wá sí èrò nínú ookàn-àyà wa láti gbé ní ọ̀nà tí ó bọlá fún Ọlọ́run. Awọn ohun tí a yan lóde òní ṣe apẹrẹ ẹri wa fun ọjọ ọlá. Bí o tilẹ̀ gbà wá ní ígbí yànju láti dúró yàtọ̀. Ǹjẹ́ kí a pinnu nínú ọkàn wa láti tẹ̀ lé Ọlọ́run tọkàntọkàn, àní nígbà tí ìpèníjà bá wà.
BIBELI KIKA: DÁNÍẸ́LÌ 1:1-8
ADURA: Olúwa, ràn mí lọwọ láti pinnu nínú ọkàn mí láti jẹ́ olotitọ sí Ọ. Ràn ìgbìyànjú mí lọwọ ki nlé gbé gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ Rẹ̀. Amin.