READY TO GIVE

THE SEED

“Let them do good, that they be rich in good works, ready to give, willing to share.” 1 Timothy 6 : 18

 

Financial prosperity is God’s will for His children. However, the kind of prosperity that God intends will not take you away from God. It is so sad to note that a lot of wealthy people are controlled by their wealth. You are supposed to possess your wealth and not the wealth possessing you. God’s plan is that you will be able to use your wealth as a servant for the expansion of the kingdom work, just like the people of old and what they were able to accomplish in their life time for the kingdom. Be ready to give sacrificially and consistently for the high calling of the Lord, this is the purpose of the wealth given to you by God, please don’t let wealth put you in bondage by not being a cheerful giver, If God was the one who gave it to you in the first place, then you should be able to freely give it back to Him.

BIBLE READING: 1 Timothy 6 : 6-7

PRAYER: Oh Lord help me to be faithful in my giving and let my wealth be for you and not

                                        ṢETAN LATI ṢE IPIN FÚN NI

IRUGBIN NAA

“Ki wọn kí o máà ṣe òòrè, kí wọn kí o máà pọ ní iṣẹ rere, ki wọn múra láti pin fún ní” 1Timoteu 6:18

 

Nini owo jẹ ifẹ Ọlọrun fun awọn ọmọ rẹ. Sibẹsibẹ, iru owo ti Ọlọrun fẹ ki o ni, ko ní  mu ọ kuro lọdọ Ọlọrun. Ó jẹ́ ìbànújẹ́ láti ṣàkíyèsí pé ọ̀pọ̀ àwọn ọlọ́rọ̀, ni ọrọ̀ wọn ń darí wọ. O yẹ ki o jẹ adari lori ọrọ̀ rẹ kii ṣe ọrọ̀ ni kí o máà dari rẹ. Ètò Ọlọ́run ni pé kí o lè lo ọrọ̀ rẹ gẹ́gẹ́ bí ìránṣẹ́ fún ìmúgbòòrò iṣẹ́ ìjọba Ọlọrun; ṣe iṣẹ  náà gẹ́gẹ́ bí àwọn ènìyàn ìgbàanì àti ohun tí wọ́n gbè ṣe ní ìgbà ayé wọn fún Ìjọba náà. Ṣetan lati ṣe ipin fun ni lọfẹ̀ ati nigbagbogbo fun ipe giga ti Oluwa, eyi ni ere idi ọrọ̀ ti Ọlọrun fi fun ọ. Jọwọ maṣe jẹ ki ọrọ́ fi ọ sinu igbekun, nipa ki o ma ba a jẹ olufunni la i sí ìtìjú. Ti o ba jẹ pe Ọlọrun ni ẹniti o fun ọ, lẹhinna o yẹ ki o ni anfani lati fi í pada fun Un lọfẹ.

BIBELI KIKA: 1Timoteu 6:6-7

ADURA: Oluwa ran mi lọwọ lati jẹ olooto ninu ohun ti a fifun mi, jẹ ki  ọrọ̀ mi máà jẹ temi ki o má ṣe jẹ ti eṣu. Ni órúkọ Jesu Kristi Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *