RESIST THE DEVIL

THE SEED
“Submit yourselves therefore to God. Resist the devil, and he will flee from you.” James 4:7

Brethren, the devil has come to steal destiny, joy and future of people and also to kill and destroy when one is least expected. Our Lord Jesus Christ is the Lamb of God, but He is also the Lion of Judah. It is true that you should be as gentle as a dove, but not when dealing with a snake (devil). Jesuse was calm and gentle while walking into the temple, but when He saw that trading was going on inside the temple, He got angry,turned their trading tables upside down and drove out the traders. That certainly wasn’t gentle, you also are the temple of the Most High God. When you see someone trying to hinder you from fulfilling your purpose, you must not handle it with gentility, you must rebuke it immediately, not all friends are your friend, we have some wolfs in sheep clothing. Mama Eve opened her door for the devil to come in and she was gentle and we know the end of the story, it is your right to rebuke anything trying to hinder your destiny. You cannot be gentle with them; you must rebuke them so that they don’t destroy you.

Will you let the devil hinder your destiny?

BIBLE READING: Ephesians 6:12

PRAYER: Father, paralyse every agent of darkness that tries to hinder me from fulfilling my purpose now, in Jesus Christ name. Every wolf in sheep clothing you are exposed in Jesus Christ name

 KỌ OJÚ ÌJÀ SÍ ÈṢÙ

IRUGBIN NAA

“Nitorina ẹ tẹriba fun Ọlọrun. Ẹ kọ ojú ìjà sí èṣù.” Jakọbu 4:7

Arakunrin, èṣù ti wa lati ji ayanmọ, ayọ ati ọjọ iwaju eniyan, ati lati pa ati run nigbati eniyan ko nireti.  Oluwa wa Jesu Kristi ni ọdọ-agutan Ọlọrun, ṣugbọn o tun jẹ kiniun ti ẹyà Juda. Otitọ ni pe o yẹ ki a jẹ onírẹlẹ bi adaba, ṣugbọn ki í ṣe nigbati a ba n kọ ju sí ejo ti o nṣe (eṣu). Jesu jẹ́ onírẹ̀lẹ̀, ṣùgbọ́n nígbà tí Ó wọ inú tẹ́ńpìlì ti Ó ri ohun tí ó burú nínú tẹ́ńpìlì náà, Ó tí àwọn tábìlì danu, Ó sì lé àwọn oníṣòwò náà jáde. Dajudaju eyi kii ṣe ìwà irẹlẹ! Iwọ pẹlu ni tẹmpili Ọlọrun Ọga-ogo.  Nigbati o ba ri ẹnikan ti o ngbiyanju lati ṣe idiwọ fun ọ, lodi si, lati mu ipinnu rẹ ṣẹ, iwọ ko gbọdọ hùwa  irẹlẹ pẹlú, o gbọdọ ba a wi lẹsẹkẹsẹ. Kii ṣe gbogbo awọn ọrẹ ni ọrẹ rẹ, a ni diẹ ninu wọn jẹ́ ikõkò ti o wọ aṣọ agutan. Mama Efa ṣi ilẹkùn rẹ, ki èṣù wọlé o si hùwa irẹlẹ,  a si mọ opin itan na, ẹtọ rẹ ni lati ba ohunkohun ti o ngbiyanju lati dena ayanmọ rẹ.  O ko le ṣe pẹlẹ pẹlu wọn, o gbọdọ ba wọn wi ki wọn ma ba pa ọ run. Ṣe iwọ yíó jẹ ki eṣu di ayanmọ rẹ lọwọ?

BIBELI KIKA: Efesu 6:12

ADURA: Baba sọ wọn  di arọ, gbogbo aṣoju okunkun to ngbiyanju lati jẹ idena fun mi lati mu ipinnu mi ṣẹ ni bayi, ni orukọ Jesu Kristi.  Gbogbo Ikooko ti o wa ninu aṣọ agutan ki o fara han ni orúkọ Jesu Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *