SECRETS OF LONGEVITY

SECRETS OF LONGEVITY

THE SEED

“You shall therefore keep His statutes and His commandments which I command you today, that it may go well with you and with your children after you, and that you may prolong your days in the land which the Lord your God is giving you for all time.” Deuteronomy 4:40 NKJV

As science is attempting to unravel the secret of Longevity, the Word of God has already unraveled this to His children long ago to give us the recipes for it.  For example, Ephesians 6:2-3 urges us to honour our parents so that our days may be long upon the earth. Other bible passages that give us secrets to Longevity include Deuteronomy 6:2 ( the fear of God);  Proverbs 3:2 (keeping to His Word), Psalms 91:15-16 (calling upon the name of the Lord), 1 Peter 3: 10-11 (refraining your tongue from evil, avoiding lies, hating evil, doing good and making peace). There is no gainsaying that eating a good and balanced diet, having a good night’s rest, regular Exercise, drinking between 6-8 glasses of water a day, eating less fat, sugar, and salt and taking time to relax will surely add to life, all of these are as important as the word of God. The place of God’s word is very important and cannot be taken for granted. As we eat to keep healthy, let’s also stick to His word. This will lengthen our days and prolong our stay on planet earth. Your lengthy days will be useful to fulfill God’s purpose on earth.

BIBLE READING: Deuteronomy 4: 39-49

PRAYER: Father, grant me the grace to live long to proclaim the name of the Lord in the Land of the living. Let not Satan use food to destroy my destiny, let me not die before my time or serve you in vain in Jesus name, Amen.

 

ÀṢÍRÍ Ẹ̀MÍ GÍGÙN

IRUGBIN NAA

“Nítoríná kí ìwọ kí ó pa ìlànà Rẹ mọ́, àti òfin Rẹ, tí mó pa láṣẹ fún ọ lí òní, kí ó lè dára fún ọ, ati fún àwọn ọmọ rẹ̀ lẹhin rẹ, àti kí ìwọ kí ó lé mú ọjọ rẹ̀ pẹ lórí ilẹ̀, tí Olúwa Ọlọ́run rẹ̀ fí fún ọ.” Deuteronomi 4:40.

Bí ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì ṣe ń gbìyànjú láti tú àṣírí pípẹ́ laye, ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ti ṣí ìsí payá fún àwọn ọmọ Rẹ̀ tipẹ́tipẹ́ láti fún wa ní àwọn ìlànà fún èyí , Fun àpẹẹrẹ, Éfésù 6:2-3 ń rọ̀ wá láti Bọ̀wọ̀ fún àwọn òbí wa kí ọjọ́ wa lè pẹ́ lori ilẹ̀ ayé. Awọn ẹsẹ Bibeli miiran ti o fun wa ni aṣiri si igbesi-aye gigun ni Deuteronomi 6: 2 (bẹru Ọlọrun) Owe 3 :2 (pipa Ọ̀rọ̀ Rẹ̀ mọ́) Orin Dafidi 91:15-16 (pipe orukọ Oluwa) 1 Peteru 3:10 – 11 (Pípa ahọn rẹ mọ kúrò nínú ibi, yí yàgò fun ìrọ, ikorira ibi, ṣíṣe réré ati wíwa àlàáfíà). Ko si a sọ dùn, nípa wi pe jíjẹ onjẹ ti o dara pẹlu àwọn èròjà inu ounjẹ, orun sísun dáradára ni alẹ, Idaraya deede, mímú ife omi mẹ́fà si mẹ́jọ ni ọjọ kan, jijẹ ọra ní wọ́nba díẹ̀, ṣùga, ati iyọ ati gbigba akoko lati sinmi; dajudaju eyi yió ṣé àfikún igbe aye. Gbogbo nkan wọnyi jẹ pataki bi ọrọ Ọlọrun. Ipo tí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run kó ṣe pataki pupọ ati pe a ko gbọdọ gba a ni yẹpẹrẹ. Bí a tí njẹun lati ni ilera, ẹ jẹ ki a tun duro tí awọn ọrọ Rẹ. Eyi yio mu awọn ọjọ wa gùn, ati pe ọjọ gigun wa yio wulo lati mu ipinnu Ọlọrun ṣẹ lori Ile-aye :-

BIBELI KIKA: Deuteronomi 4: 39-49.

ADURA: Baba, fun mi ni Ore-ofe lati lé ni ẹmi gígùn lati kede orúkọ Oluwa ni ilẹ alaaye. Ma jeki Sàtánì lo OÚNJẸ lati ba ayanmọ mi jẹ́, ma jẹ́ ki n ku ṣáájú asiko mi tabi sin Ọ lasan ni orúkọ Jesu. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *