SEEK THE LORD EARLY
THE SEED
“O God, thou art my God, early will I seek thee: my soul thirsteth for thee, my flesh longeth for thee in a dry and thirsty land, where no water is. Psalms 63:1
There are three periods in a man’s life; morning, afternoon and evening period just like in a day. The scripture above is talking about waking up early in the morning to seek the face of God, praising, praying and listening to what He has to say to us.
To seek the Lord early can also mean to set out to know and to do the will of the Lord at an early age, as a small child and at the useful age of a youth, when one still has the strength and power to do whatever one wishes to do.
An early age is a very acceptable time to actively show our love towards the God that gave us life and purpose. This negates the erroneous idea of some people, that running life’s race of achievements while young, then create time to serve and do the will of the Lord at an old age. It might be too late by that time, as the devil may not even allow some to reach old age and for some, with God’s intervention, they will.
Remember now thy creator in the days of thy youth, while the evil days come not, nor the years draw nigh, when thou shall say, I have no pleasure in them. Ecclesiastes 12:1. PRAYER
I receive the grace to love the Lord and do His will very early in my youthful age in Jesus name. BIBLE READINGS: Psalm 63:1-8
WA OLUWA NI KUTUKUTU
IRÚGBÌN NÁÀ
“Olorun, iwọ lí Ọlọrun mi, ní kùtùkùtù lí èmi o má ṣafẹri rẹ̀; òùngbẹ rẹ ngbẹ ọkàn mi, ẹran ara mi fà sí ọ ni ilẹ gbigbẹ, àti ilẹ tí npongbe, nibiti omi kò gbe sí”. Orin Dáfídì 63:1
Igba meta ni o wà nínú ayé ènìyàn igba owuro, igba òsán, ati igba ale bi o ti ṣe wa nínú ọjọ kan niyi. Ẹkọ tí a kà nsọ nipa jiji ni kùtùkùtù òwúrò lati wa oju Olorun, lati yin, lati gbàdúrà ati lati fetí sí ohun tí O fẹ bá wá sọ.
Lati wá oju Oluwa ni kùtùkùtù le tumọ sí wíwá láti mọ àti lati ṣe ìfẹ Oluwa bi ọjọ ori wá tí mọ, gẹgẹ bí odomode ati nigba ti a wa ni ọdọ. Nigbati a sì ni agbára láti ṣe ohun ti o wun wa lati ṣe.
Àsìkò yi jẹ asiko itẹwọgba lati fi ìfẹ wa hàn sí Ọlọrun ti o fun wá ni ero ati iwa laa ye. Eleyi tako èrò inú àwọn ènìyàn kan ti o lodi; wipe lati sa eré ìje fún aseyori nigbati a wa ni ọdọ. Lẹhin eyi ki a wa aaye lati ṣe ìfẹ Oluwa ni ọjọ ogbó wa. O ti le ti bọ sori lasiko náà; nitori satani lè má yọnda ọpọ èèyàn láti lè dé ọjọ ogbó wọn. Ọpọ sì lè dé ọjọ ogbó ti Olorun ba da sí ọrọ wọn.
Rántí ẹlẹdà rẹ nisinsinyi li ọjọ
ADURA
Mo gba ore ife lati feran Oluwa ati lati se ife re ni ibere odo mi ni oruko Jesu
BIBELI KIKA: Orin Dafidi 63:1-8