THE SEED
“I will instruct you and teach you in the way you should go; I will counsel you with my eye upon you.“ Psalm 2:8 ESV
As beloved of Christ we find solace and direction in seeking God’s guidance at every point of our lives. At this crucial period when we are about to end a year and enter a new one, it becomes important for us to seek God’s guidance so that we can understand His plans for us in the new year. In this time of uncertainty and unrest in our world today, our opening scripture reminds us of the promise of God to instruct us and teach us in the way we should go; God promised to counsel us with His loving eye on us. This promise calls us to seek God’s guidance for the manifestation of His promise in our lives. Beloved, let’s invite His counsel into our lives to receive His guidance, creating an intimate connection that goes beyond earthly challenges through prayer and meditation on God’s Word. Matthew 7 reinforces this as Jesus encourages us, to ask, seek and knock. For everyone who asks receives; the one who seeks finds; and to the one who knocks, the door will be opened.” Our journey of seeking God’s guidance involves persistent prayer, unwavering faith, and a genuine desire to align our will with His divine plan in the new year.
BIBLE READINGS: Matthew 7:7-11
PRAYER: Lord, let me find direction and peace to navigate life in your will. Amen
WIWA ITOSONA OLORUN
IRUGBIN NAA
Emi o fi ese re le ona, emi o si ko o li ona ti iwo o rin; emi o ma fi oju mi to o. Orin Dafidi 32:8
Gege bi Olufe Kristi, itunu wa ninu ki Olorun to wa sona ni igbesi aye wa. Ni igba ti a way ii, ti odun lo si opin yii, ti a si fe lo si odun titun, o je Pataki fun wa itosona Olorun, ki a le mo ipinu re fun wani odun titun ti a fe wo yii. Ni asiko ti a wa yii, ese Bibeli yii ran wa leti awon ileri ti Oluwa ti se fun wa, ati ona ti a o gba; Oluwa se Ileri fun wa lati to wa si ona pelu oju ife re. Awon Ileri yii je ki a mo itosona fun awon ileri re ninu aye wa. Ayanfe, e je ki a pe imoran Olorun sokale sinu aye wa, lati le gba itosona re, lati le ni asopo timotimo lati le ma gbadura ati lati ma jiroro ninu oro Olorun. Ihinrere Matthew, ori 7 so wipe Jesu ba wa soro lati beere, ki a wa kiri, ki a si kan ilekun. Nitori eni ti o ba beere yio ri gba, eni to ba si wa kiri, yio ri, eni ti o ba si kan ilekun ni a o si fun. A nilo adura gbigba nigba gbogbo, ati igbagbo ti k nye, ati ife ijinle lati le w ani ibamu pelu ohun ti Olorun fe, pelu ife re lati Olrun wa.
BIBELI KIKA: Matthew 7:7-11
ADURA: Olorun, gegebi mo se wa itosona re, ma se to mi sona nikan, sugbon fun mi ni alaafia lati rin ninu ase re, Amen.