Sowing Thy Seeds

THE SEED
“Another parable put he forth unto them, saying, The kingdom of heaven is like to a grain of mustard seed, which a man took, and sowed in his field:” Matthew 13:31

Thy seed is any gift, any skill or talent that God has provided for you to sow into the lives of others around you for the harvest that you are praying for. We were all created with special seeds, the tragedy however is that many of us never get to use 10% of the seeds that we have in our lives because we just simply never asked the person who gave us the seed, which is God Almighty, to show us how we can transform those seeds into powerful harvests in our lives. Imperatively, the secret to every harvest we have ever desired is in the seed that we have been given. We must recognize all the seeds God has stored within us and plant them for our desired harvest.

BIBLE READING: Matthew 13

PRAYER: Lord, as I journey through the month, my desire should be to pray and ask You to show me how I can transform every seed that You have given me into a bounteous harvest to achieve everything that I need in life and build the house of God accordingly.

GBIGBIN IRUGBIN RE

IRUGBIN NAA
“O si pa owe miran wipe, Ijọba ọrun dabi koro irugbin musitadi kan, ti ọkunrin kan mu, ti o si gbìn sinu oko re.” Matteu 13:31

Irugbin rẹe jẹ eyikeyi ẹbun, eyikeyi ọgbọn tabi talenti ti Ọlọrun ti pese fun ọ lati gbìn sinu awọn igbesi aye awọn elomiran ni ayika rẹ fun ikore ti o n gbadura fun. Gbogbo wa ni a da pẹlu irugbin pataki, o se ni laanu pe opolọpo ni ko lo to idasi mewà ninu ogorun awọn irugbin ti a ni ninu igbesi aye wa nitori a ko beere lọwọ ẹni ti o fun wa ni irugbin, ti o jẹ Ọlọrun Olodumare, Lati fihan wa bi a ṣe le so irugbin di ikore ti o lagbara ninu igbesi aye wa. Ni pataki julo, aṣiri ti n be ninu ikore ti Okan wa Fe wa ninu irugbin ti a fi fun wa. A gbọdọ mọ gbogbo awọn irugbin ti Ọlọrun ti fipamọ sinu wa ki o si gbin wọn fun ikore ti a fẹ.

BIBELI KIKA: MATIU 13

ADURA: Oluwa, bi a ṣe n rin irin ajo ni oṣu yi, ki ifẹ mi ki o jẹ lati gbadura ati beere lọwọ Ọlọrun lati fihan mi bi a ṣe le yi gbogbo irugbin ti o ti fi fun wa pada si ikore lọpọlọpọ lati ṣaṣeyọri ohun gbogbo ti a nilo ninu aye ati kọ ile Olorun ni ibamu.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *