The Battle Belongs To Him

THE SEED
“And the God of peace shall bruise Satan under your feet shortly. The grace of our Lord Jesus Christ be with you. Amen” Romans 16:20

In the scripture above, this promise of victory was literally fulfilled in the person of our Lord Jesus Christ. And His people shall dwell in peace through the triumph of Jesus Christ. That is our bright, confident hope as Christians. The Christian hope is not an exercise in wish fulfilment of make believe. Nor is our confidence rooted in triumphalist overestimation of our own abilities. It’s not an exercise in arrogance and self-assertion. Our hope is not a function of earthly fixes to social ills. Our confidence and our hope lies in the baby of Bethlehem, born of a woman who has crushed the serpent’s head at the cross. That is, the victory of the seed of the woman, the Lord Jesus Christ, shall be our victory also one day soon. Every temptation will cease. All the affliction and opposition, all the cultural pressure to conform or to tone it down or to back off will be over. Because the battle belongs to the Lord.

BIBLE READING: Romans 16

PRAYER: Lord, may the God of peace bruise Satan under my feet shortly. May the grace of our Lord Jesus Christ be with me. Amen

OGUN NAA TI OLUWA NI

IRUGBIN NAA
“Olorun alafia yoo Fi satani pamo sabe ese re. Ore-ọfẹ Jesu Kristi Oluwa wa ki o wà pẹlu nyin. Àmín.” Róòmù 16:20

Ninu iwe-mimọ ti o wa loke yi, ileri iṣẹgun yi ni a ti muṣẹ nipase Oluwa wa Jesu Kristi.Àwọn ènìyàn re yíò sì máa gbé ní àlàáfíà nípa ìṣẹ́gun Jésù Krístì. Iyẹn ni ireti didan ati igboya wa gẹgẹ bi Kristiani. Ireti Onigbagbọ kii ṣe ise nipa mimu eniyan gbagbọ. Bẹ́e ni ìgbẹ́kelé wa kò fìdí múle nínú ṣíṣe àṣejù nínú ìṣẹ́gun ti àwọn agbára tiwa fúnra wa. Kii ṣe ise nipa igberaga ati imuduro ara ẹni. Ireti wa kii ṣe iṣẹ nipa titu awon ise ti o to bàje ninu awujo se. Igbẹkẹle ati ireti wa wa ninu ọmọ ti Betlehemu, ti a bi lati ọdọ obinrin kan ti o ti fọ ori ejo ni agbelebu. Igboya atí ireti wa was ninu omọ ti a bi ni Bethlehemu nípase obinrin naa, Oluwa Jesu Kristi, yoo jẹ iṣẹgun wa paapaa ni ọjọ kan laipẹ. Gbogbo idanwo yoo dẹkun. Gbogbo ipọnju ati atako, gbogbo aṣa, ipa tabi ifasehin yoo pari.Nitoripe ti Oluwa ni ogun na.

BIBELI KIKA: Róòmù 16

ADURA: Àti pé Ọlọ́run àlàáfíà yóò pa Sátánì mọ́ sábẹ́ ẹse yín láìpẹ́. Ore-ọfẹ Jesu Kristi Oluwa wa ki o wà pẹlu nyin. Amin

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *