The Depth Of The Power Of Thanksgiving

THE SEED
“For I received from the Lord that which I also delivered to you: that the Lord Jesus on the same night in which He was betrayed took bread; and when He had given thanks, He broke it…” 1 Corinthians 11:23-24

On the night prior to His crucifixion, Jesus shared the Passover meal with His disciples. There, He organized the lovely act of fellowship (communion) which we share thousands of years after. That night, as He remained in the actual shadow of the cross, as He tore the bread that would always represent His body, He expressed appreciation (Thanksgiving). Realizing that He was bound for the cross, He offered gratitude. He frequently communicated thanks all through His life on earth. At the point when He held up a kid’s pitiful lunch, He offered gratitude as He ate and divide the fish to take care of 5,000 individuals before collecting the leftovers. As He wept outside the tomb of His dear friend, Lazarus, He paused to pray, “Father, I thank You that You have heard Me” (John 11:41). Moments later, He called His dead friend back to the land of the living and into the arms of his grateful sisters. The soul of appreciation releases the working hand of God in every circumstance. Could it be said that you are exploring a tempest or walking through a dull valley? Find a place of prayer and offer thanks to God. Your appreciation will welcome His presence, provision, and power into each area of brokenness.

PRAYER
Heavenly Father, teach me to be thankful all the days of my life. Amen

BIBLE READINGS: 1 Thessalonians 5:16-18; Psalm 100

IJINLE NIPA AGBARA IDUPE
IRUGBIN NAA
“Nitoripe lowo Oluwa li emi gba eyiti mo si ti fi fun yin, pe Jesu Oluwa li oru ojo naa ti a fi I han, O mu akara, nigba ti O si ti dupe, O bu u.” Korinti 11:23-24

Ni oru ti o saju ojo ti a kan an mo agbalebu, Jesu je ounje ajo irekoja pelu awon omo ehin Re, nibe ni o ti se ipejopo (idapo) eyi ti a n se ni opo egberun odun leyin re. Ni oru naa, ni bi o ti n wo bi agbelebu na yio ti ri, O bu akara, eyi ti o duro gege bi ara re, o dupe. O mo wipe a ran on lati wa ku lori igi agbelebu, O dupe. Nigba de igba ni o dupe ni igba aye re. Nigba ti o mu ounje omo kekere, O dupe, O je, O si fi bo egberun marun eniyan ki won to ko ajeku. Bi O ti
sokun ni enu iboji ore Re Lasaru, o gbadura wipe “Baba, mo dupe lowo Re nitoripe o maa n gbo temi” (Johannu 11:41). Leyin eyi, O pe ore Re pada saye, O si fi le awon arabinrin re lowo. Okan ti o ba moore, a maa fa owo Olorun ti n sise ninu isele gbogbo. Nje o n la ohun kan tabi ikeji koja? Wa ibi adura, ki o si fi ope fun Olorun. Ope re yio mu ki Olorun sokale, pese fun o, yio si fun o lagbara ni ibi gbogbo ti aare ti mu o.

ADURA
Baba wa orun, ko mi lati maa dupe ni gbogbo ojo aye mi. Amin

BIBELI KIKA: 1 Thessalonika 5:16-18; Orin Dafidi 100

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *