THE GIFT OF GOD’S PRESENCE

THE SEED

”Therefore the Lord Himself will give you a sign: Behold, the virgin shall conceive and bear a Son, and shall call His name Emmanuel.“ Isaiah 7:14 NKJV

In December, for those who can afford it, we exchange gifts to express our love and appreciation for one another, though not everyone can give these gifts because of the economic situation of the world today. However, God has made provision for the most precious gift ever given, to be shared among the brethren which is God’s presence with us. In this season, let’s meditate on this precious gift, acknowledge it and cherish it, believing that with God’s presence in our lives, it becomes impossible to lack our needs for the celebration of Christ’s birth. The birth of Jesus signifies God’s desire to dwell among us, to be present in our lives; to lead, direct and connect us with our destiny helpers, to fight our battle and give us victory. To silence our enemies and put songs of praise and joy in our mouths. As we make preparations to celebrate Christmas, let us not forget the gift of God’s presence. As we celebrate with loved ones, remember that the greatest gift of all is Emmanuel, “God with us.” This December, seek His presence in prayer, in the Word, and in the faces of those you encounter.

BIBLE READINGS:  Matthew 1:20 – 23

PRAYER: Father, I thank you for the gift of your presence in my life, continue to be with me now and forever in Jesus’ name. Amen.

 

Ẹ̀BÙN WÍWÀ LÁÀYÈ ỌLỌ́RUN

IRUGBIN NAA

Nitorinaa Olúwa tìkára rẹ yió fún yín ní ẹ̀bùn kan, Kíyèsí wúńdíá kan yíò lóyún, yió sí bí ọmọkùnrin kan, yió sí pé orúkọ rẹ ní Immanueli. Isaiah 7:14

Ni Oṣu Kejìlá, fun awọn ti o ni anfani, lati ṣe ipaarọ awọn ẹbun láàárín ara wọ́n, a nṣe eleyi  làti ṣé afihan ifẹ ati imọriri fun ara wa, botilẹjẹpe kii ṣe gbogbo eniyan lo le pín awọn ẹbun wọnyi nitori ipo iṣuna ọrọ-aje ti agbaye loni.  Bí ó ti wù kí ó rí, Ọlọrun ti ṣe ìpèsè fún àwọn ẹ̀bùn to  ṣe iyebíye jùlọ tí a tí fifúnni láti pín láàrin àwọn ará, tí ó jẹ́ wíwà  Ọlọrun pẹ̀lú wa. Ní àsìkò yí ẹ jẹ́ kí a ṣàṣàrò lórí ẹ̀bùn iyebíye yìí, ki a mọ rírí rẹ̀, kí a sì ṣìkẹ́ rẹ̀; ní gbígbàgbọ́ pé pẹ̀lú wíwà Ọlọrun nínú ìgbésí-ayé wa, ó di mímọ̀ ki o jẹ́ pe o ṣe aláìní  fun ayẹyẹ ibi Kristi. Ibí Jesu n tọka si ifẹ Ọlọrun lati gbe laarin wa,  lati wa ninu igbesi aye wa; lati ṣe itọsọna, idari ati so wa pọ pẹlu awọn oluranlọwọ ayanmọ wa, lati ja ogun wa ki o si fun wa ni iṣẹgun.  Lati pa awọn ọta wa lẹnu mọ́, ati fifi orin iyin ati ayọ̀ si wa lenu. Bi a ti ngbaradi fun ayẹyẹ Kérésìmesì, ẹ ma jẹ́kí a gbàgbé ẹ̀bùn ìwà láàyè Ọlọrun. Bi a ti ṣe ńṣe ayẹyẹ pẹ̀lú awọn olólùfẹ́ wa ẹ jẹ́ kí a rántí pé ẹ̀bùn tí ó ga jùlọ ni Emmanueli, “Ọlọrun wà pẹ̀lú wa.” Ninu oṣù kejìlá yi, wá iwa láàyè Rẹ ninu adura, ninu Ọ̀rọ̀, ati

níwájú àwọn ti ẹ ba pàdé.

BIBELI KIKA:  Mátíù 1:20-23

ADURA: Baba, Mo dupẹ lọwọ Rẹ fún ẹbun wiwa Rẹ nínú ìgbésí aye mi, tẹsiwaju lati wa pẹlu mi ni báyì ati lailai ni orúkọ Jesu Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *