THE SEED
“Offer hospitality to one another without grumbling.” 1 Peter 4:9
But the robust hospitality of the Scriptures is not a welcome based on how much cash (or plastic) you have in your wallet to pay for a room and a meal. It’s not even confined to people who are “like ourselves.” The hospitality Scripture speaks of is typically focused on people different from ourselves. Many of us have a certain fear of strangers. We’re intimidated by people who dress, eat, and talk differently than we do. But biblical hospitality looks beyond differences to see similarities—to recognize others as fellow image bearers of God. This hospitality is an act of welcoming grace—and therefore participates in the very dynamic of the character of Jesus Christ. One day Sarah and Abraham welcomed visitors who were actually the Lord and his angels (see Hebrews 13:2). Whom in your community do you need to welcome in the name of our Lord?
BIBLE READING: GENESIS 18:1-8
PRAYER: Father, grant us the grace to overcome our fears and welcome people who need hospitality, that we may share the love we have received from you. In Jesus name, Amen.
EBUN ALEJO SISE
IRUGBIN NAA
“Ẹ mã ṣe aájò àlejò si ara nyin laisi ìkùnsínú.” 1 Pétérù 4:9
Sise alejò nla eyi ti o se itewogba ko da lori iye owo ti ẹniyan naa ninu apamọwọ rẹ lati sanwo fun Ile itura tàbí ounje. Awon eleyi ko wa fun awọn eniyan ti o dabi Ara wa nikan. Alejò sise ti Iwe Mímo so nipa re ko da lori awon enìyàn tí ó yàtọ̀ sí awa fun Ra wa. Ọpọlọpọ wa ni o n berù awon ajoji kan. Àwọn ẹniyan ti o n mura, ti o n jeun tàbí soro ni onà ti o yàto si ti wa ni a maa n beru. Alejò sise ni ibaamu pelú tí Bíbélì kọjá ìyàtọ̀ eleyameya, eyi ti o ri àwọn ẹlòmíràn gege bí aworan Ọlorun. Alejo sise yi je Oore-ofe ikonimora ati nitori naa o ṣe alabapin ninu agbara iwa ti Jesu Kristi. Ni ọjọ kan Sarah ati Abraham gba awọn alejo ti o jẹ Oluwa ati awọn angẹli rẹ nitootọ (wo Heberu 13:2). Tani ni agbegbe rẹ ni o nilo lati se ni alejò ni orukọ Oluwa wa?
BIBELI KIKA: Jenesisi 18:1-8
ADURA: Baba, fun wa ni oore-ọfẹ lati bori awọn ibẹru wa ati ki o gba awọn eniyan ti o nilo alejò, ki a le pin ifẹ ti a ti gba lọwọ rẹ. Ni oruko Jesu Amin.