The Hand Of God

THE SEED
Thy right hand, O LORD, is become Glorious in Power : thy right hand, O LORD, hath dashed in pieces the enemy.

When someone says God’s hand is on you, it usually means that God is working wonders in your life. The hands of God represent His power and ability to work to accomplish His will, God’s right hand represents His ultimate Authority and Dominance. We know that God is all-powerful, but when we speak of God’s right-hand, it’s our way of trying to express the power with which God is moving in man’s lives. Brethren, is there any challenges or difficulties you are going through? Be calm and courageous because immediately the hand of God for good rest upon your situation there will be solutions. You need not worry or loose hope, God is there by your side, look up to His Holy hill, render your prayers, and praises and uphold your faith. The Israelites suffered a great deal in the hands of the Egyptians, but by the time they called on the Lord in prayer, God hearkened to their cry and looked down from Heaven, He performed so many wonders and stretch out His Mighty hand that parted the Red sea for them to move away from the land of slavery to the land that flows with honey. He smote their enemies right in their presence, God can do more for you and those horrific occurrences around you will be silenced and turn to testimonies to give Glory to the Name of the Lord.

BIBLE READING: Exodus. 15 : 6 – 16

PRAYER: We pray oh Lord, let your right Hands for good rest upon us all in Jesus Mighty Name. Amen.

OWO OLORUN

IRUGBIN NAA
OLUWA, ọwọ́ otún rẹ di ológo ninu agbára: OLUWA, ọwọ́ otún rẹ ti fọ́ àwọn otá túútúú.Eksodu. 15:6 (KJV).

Nigba ti ẹnikan ba sọ pe ọwọ Ọlọrun wa lara rẹ, o maa n tumọ si pe Ọlọrun n ṣiṣẹ iyanu ninu aye rẹ. Ọwọ́ Ọlọ́run dúró fún agbára re láti ṣiṣẹ́ láti mú ìfẹ́ re ṣẹ, Ọwọ́ otún Ọlọ́run dúró fún Àṣẹ Rẹ̀ tó ga jùlọ àti Ìṣàkóso Re. A mo pé Ọlọ́run jẹ́ alágbára ninu oun gbogbo, ṣùgbọ́n nígbà tí a bá ń soro nípa ọwọ́ otún Ọlọ́run, ó jẹ́ onà láti sọ wipe agbára Ọlọ́run ń rìn nínú ìgbésí ayé ènìyàn. Ara, nje awon idojuko kan wa ti eyin n la kọjá bi? Ṣe suuru, ki o si ni igboya nitori nikete ti ọwọ Ọlọrun rere bati fowo kan ìṣòro re, onà abayo yoo wa. Iwọ ko nilo lati ko okan re soke tabi so ireti nu, Ọlọrun wa pelú re, gboju soke si oke Mimọ Rẹ, gbadura, yin n, ki o si mu igbagbọ rẹ duro. Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jìyà púpo lọ́wọ́ àwọn ará Íjíbítì, ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n ké pe Olúwa nínú àdúrà, Ọlọ́run gbọ́ igbe wọn, ó sì bojú wole láti orun. O sise iyanu ti o Po,o si na owo agbara re lati pin okun pupa niya lati lọ kuro ni ilẹ-ẹru si ilẹ ti nṣàn fun oyin. Ó kọlu àwọn otá wọn ní ojú wọn, Ọlọ́run lè ṣe púpo sí i fún ọ, àwọn ìṣele tí ń bani lẹ́rù tí ó yí ọ ká yóò sì pa á lẹ́nu mọ́, wọn yóò sì yípadà sí erí láti fi Ògo fún orúkọ Olúwa.

BIBELI KIKA: Eksodu. 15:6-16

ADURA: A ngbadura Oluwa, jeki Owo otun re fun rere wa ni ori aye wa ni Oruko Jesu Alagbara. Amin.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *