THE HEART OF MAN

THE SEED

“The heart is deceitful above all things And desperately wicked; Who can know it?“  Jeremiah 17:9 NKJV

The heart of man is considered to be the most vital organ, the seat of life and strength. Though it plays a significant role in helping to maintain a healthy circulatory system in physical function, it’s however divinely overshadowed by its overall Spiritual function. It is believed that the heart is inclusive of the mind, soul and Spirit of man and therefore,  it has remained God’s only “ACCESS” point to mankind. The only medium that authorises God’s entrance into our lives unhindered as well as the devil’s. As a child of God, what do you have in your heart? Evil or Good? Happiness or sadness? Curse or Blessings? Hatred or Love? What makes the heart of a man desperately wicked as pointed out in the opening verse is the evil thoughts that we allow to penetrate, entertain and remain there. To keep our hearts pure before God we need to think deeply about the love of God and allow it to dwell in our hearts so that our hearts will be filled with love towards other people and be built to reject evil that corrupt the heart. This is the only way you too can get through to the Almighty, because God Himself is L O V E. Do not harbour evil in your heart, it makes the heart wicked.

BIBLE READINGS:  Deuteronomy 6:4-6

PRAYER: Lord I pray help me with the Power of the Holy Spirit to always fill my heart with Joy, Peace and especially love for all your creations.

 

OKAN ENIYAN

IRUGBIN NAA

Okan eniyan kun fun etan ju ohun gbogbo lo, o koja ti a le wosan, ta ni eyi le ye? Jeremiah 17: 9

Okan Eniyan ni o je eys ara ti o se Pataki ju lo, ijoko iye ati agbara. Bi o tile je pe, o nse opolopo ise ni ago ara yii, sugbon o nse ise emi. 

A Gbagbo wipe ati okan, aiya, ati emi lo wa ni inu okan wa, nitori naa, oun ni ONA ti Oluwa fi n ba eda soro. Ons kan ti Olorun gba nba wa soro, ti esu na ngba lati ba soro ni eyi. Gege bi Omo Olorun, kini o wa ni Okan re yii? Ibi ni tabi rere? Idunnu tabi ikoro? Eegun tabi Ibukun? Ikorira tabi Ife? Ohun ti o ma mu ki okan eniyan kun fun iwa ika gegebi Bibeli ti so ni ero buburu ti a nro ti si pinnu lati se ni okan wa. Lati je ki okan wa mo niwaju Olorun, a gbudo ma ro nipa ife ti Olorun ni si wa, ki a si jeki o ma gbe ni okan wa, ki okan wa le kun fun Ife si eniyan gbogbo, ka si le ko Ibi sile, ki o ma ba se akoba fun okan wa. Ona kan ti a fi le sunmo Olorun ni eyi, nitori Ife kuku ni Olorun. Ma se gbiro Ibi ni okan re,  nitori o ma je ki okan kun fun Ibi ni

BIBELI KIKA: Deut 6:4–6

ADURA: Olorun mo gbadura, ran mi low opelu agbara Emi mimo, lati le fi ayo kun okan mi,  alaafia, papa julo, ife fun gbogbo ise owo re. 

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *