THE SEED
”But when he, the Spirit of truth, comes, he will guide you into all the truth. He will not speak on his own; he will speak only what he hears, and he will tell you what is yet to come”. John 16:13 NIV
The Holy Spirit, sent by the Father, is our divine compass showing and leading us into all truth. In times of uncertainty, we find reassurance in knowing that the Spirit doesn’t speak on its own authority but declares the truths revealed by the Almighty God. Acknowledging the Spirit’s role as our guide allows us to surrender our limited understanding to the divine wisdom that surpasses all, thereby allowing us to see the Holy Spirit, as the revealer of truth, the light that illuminates our journey paths, guiding us step by step through the darkness of life. the Holy Spirit’s guidance leads us away from worldly temptations towards a life aligned with God’s will. As true children of God’s kingdom, let us embrace the Spirit’s guidance with open hearts and receptive spirits. Rather than being repulsive and wise in our understanding as it is being seen among believers today. It is only by the guidance of the Holy Spirit that we can prevail over the tricks and trials of the devil. Through prayer, meditation on God’s Word, and a surrendered will, we position ourselves to be led by the Spirit into the fullness of truth and the abundant life God has prepared for us.
BIBLE READINGS: 1 Corinthians 2:10-14
PRAYER: Lord, help me to always be receptive to the faithful guide of your Spirit, steering me towards the eternal promises of God. Amen.
ÌTỌ́SỌ́NÀ TI Ẹ̀MÍ MÍMỌ́
IRUGBIN NAA
“Ṣùgbọ́n nigbati òun, àní ẹmi òtítọ́ ni ba dé, yió tọ́ yín sí ọ̀nà òtítọ́ gbogbo; nítorí kí yío sọ tí ara rẹ̀; ṣùgbọ́n ohunkohun ti o bá gbọ, òun ni yío máà sọ: yió sí sọ ohun tí mbọ̀ fún yín” Jòhánù 26:13
Ẹmi Mimọ ti baba fi ranṣẹ jẹ olùtọ́sọ́nà atọrunwa ti nfi idari wa han sinu otitọ gbogbo. Ni awọn akoko aidaniloju a rii ifini lọ́kàn balẹ̀ ni mi mọ pe ẹmi ko sọrọ àṣẹ fun rararẹ ṣugbọn o nfi otitọ Ọlọrun Olodumare han. Gbigba ipa ti ẹmi, gẹgẹbi itọsọna wa, gba wa laaye lati fi oye wa ti o ni odiwon sínú ọgbọn atọrunwa ti o kọja ohùn gbogbo. Nitorinaa gbigba wa laaye lati ri Ẹmi Mimọ bi olufihan otitọ imọlẹ ti o tan imọlẹ si àwọn ipa-ọna irin-ajo wa, ti n dari wa lẹsẹsẹ la àárín okunkun ilé ayé. Itọsọna ẹmi mimọ n dari wa lọ kuro ninu awọn idanwo ti aiye si ọna igbesi aye ti o ni ibamu pẹlu ifẹ Ọlọrun. Gẹgẹbi awọn ọmọ otitọ ti Ijọba Ọlọrun, ẹ jẹ ki a gba itọsọna awọn ẹmi pẹlu ọkan ti o ṣí payá lati gba awọn ẹmi. Dípò ki o jẹ irira ati ọlọgbọn ninu oye wa, bi o ti wa laarin awọn onigbagbọ loni. Ó jẹ nipasẹ itọsọna ti ẹmi nikan ṣoṣo ni a le bori lori awọn ẹtan ati awọn idanwo Eṣu. Nipasẹ adura, àṣàrò lori ọrọ Ọlọrun, a fi ara wa silẹ fún idari nipasẹ Ẹmi Mimọ sinu kikun otitọ ati igbe aye lọpọlọpọ, ti Ọlọrun pese fun wa.
BIBELI KIKA: Kọrinti Kinni 2:10-14
ADURA: Oluwa ràn mí lọ́wọ́ láti máa tẹ́tí sílẹ̀ nígbà gbogbo sí ìtọ́sọ́nà ótítọ ́ ẹ̀mí Rẹ, ti o ńdarí mi sí àwọn ìlérí Ọlọ́run ayérayé. Amin