The Immediacy Of Missions

THE SEED
“Say not ye, There are yet four months, and then cometh harvest? behold, I say unto you, Lift up your eyes, and look on the fields; for they are white already to harvest.” John 4:35

We live in a fast paced world, that the impulsive eruption of missionary zeal no longer characterizes our churches. We became more concerned with saving face, than saving souls. We became organized, systematized, anesthetized, domesticated. Our missionaries are out of sight and out of mind. We are more concerned with providing funds for the new auditorium to beat competitors and parking lot, than we are about whether or not our missionary programs are adequately financed. We attend self-help seminars to build up our self-confidence and self-esteem and fill our self-centered and self-seeking needs. But the yearning and the heart of God continues to beat for the nations. His vision has not diminished and neither has He relinquished His purpose. He is still saying to you and to me: “Go, get up, get out, get going and win souls”.

BIBLE READING: John 4

PRAYER: Lord, please help me to win any souls for You this year, in Jesus name.

ISE IHINRERE LESEKESE

IRUGBIN NAA
“Eyin ko ha wi pe, O ku osu merin, nigbana ni ikore de? kiyesi i, mo wi fun nyin, Ẹ gbé oju nyin soke, ki ẹ si wò awọn oko; nitoriti nwọn ti funfun fun ikore.” Jòhánù 4:35

A ń gbé nínú ayé tí ó n kanju ti ko si itara fun ise ìránṣe ninu ijo. Oun ti o je wa logun ni wipe igbala oju dipo igbala okan.A je eni ti o seto. A ko Fi awon òjíṣe Ọlorun sokan mo. A bìkítà gan-an nípa pípèsè owó fún gbogàn tuntun náà láti ṣegun àwọn olùdíje àti ibi ìgboko sí, je wa logun ju bí a ṣe ń nawo si awon ètò ihinrere lo. O te wa lorun Lati lo si awon idanileko ti yio ran Ara eni lowo, ti yio funni ni igboya ti yio so eniyan di eni Pataki. Ṣugbọn ifẹ ati ọkan Ọlọrun tẹsiwaju lati lu fun awọn orilẹ-ede. Ìran re kò dín kù, beeni kò sì kọ ète re síle. O tun n sọ fun iwọ ati emi pe: “Lọ, dide, jade, ki o si Jere awon Okan.

BIBELI KIKA: Jòhánù 4

ADURA: Oluwa, jowo ranmilowo lati jere okan fun O ni odun yi, ni oruko Jesu.

Leave a comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *