THE SEED
“Then we which are alive and remain shall be caught up together with them in the clouds, to meet the Lord in the air: and so shall we ever be with the Lord.” – 1 Thessalonians 4:17
The rapture is the catching away of believers to meet the Lord in the sky, marking the beginning of eternity with Him and the start of the Great Tribulation for the unsaved. Those who live with eternity in mind prioritize God’s kingdom over material possessions and prepare themselves spiritually. We, the believers are called to examine our lives continually, ensure that we are ready for Christ’s return, and actively share the gospel. Living with this hope motivates holy living, urgent evangelism, and devotion to God, making us ready to be part of the glorious event when Christ comes for His Church.
BIBLE READINGS: 1 Thessalonians 4:13–18 (KJV)
PRAYER: Lord, help me to live a life ready for Your return and to prepare others for Your kingdom, in Jesus’ name. Amen.
IJINLE IGBASOKE
IRUGBIN NAA
Nigbana li a ó si gbà awa ti o wà lãye ti o si kù lẹhin soke pẹlu wọn sinu awọsanma, lati pade Oluwa li oju ọrun: bẹ̃li awa ó si ma wà titi lai lọdọ Oluwa. I TẸSALONIKA 4:17
Igbasoke ni gbigba awon ayanfe soke lati pade Olorun ni awosanmo, eyi ni ibere ayeraye pelu Re ati ibere iponju nla fun awon ti ko ni igbala. Awon ti nlo aye won pelu ayeraye ninu okan won maa nfi ti ijoba Orun saju dipo ohun aye, nwon a si maa murasile ninu emi. Awa onigbagbo, a ni lati maa ye ara wa wo nigba de igba, ki a ri wipe a wa ni imurasile fun ipadabo Kristi, ki a si maa soro ihinrere. Gbigbe pelu ireti yii mas nmu wa gbe igbe aye iwa mimo, pipolongo ihinrere, ati ifaraji fun Olorun, eyi yoo mu wa setan lati ni ipin ninu isele ologo naa nigbati Kristi ba de kati ko ijo Re.
BIBELI KIKA: I Tesalonika 4: 13-18
ADURA: Oluwa, ranmilowo ki nle gbe igbe aye mi ni imurasile fun ipadabo Re, ki nsi le mu awon elomiran setan fun ijoba Re, ni oruko Jesu. Amin